Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Ilé iṣé NNPC Foundation Ti Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Iṣé Abẹ Ọfẹ Fún Àìsàn Ojú Ni Ìpínlẹ̀ Niger.
Ilé iṣé NNPC Foundation ti ṣe ètò ìtọ́jú iṣé abẹ ọfẹ fún àìsàn ojú fún àwọn ènìyàn Ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta ni ìpínlẹ̀ Niger.
Iyaafin Emmanuela Arukwe tó jẹ adari àgbà pátápátá fún ilẹ Isé NNPC Foundation ló sọ èyí di mímọ̀ ni Minna ni ọjọ ẹti.…
Àjọ NCDC Ṣe Ìkìlọ Nípa Àìsàn Kábìkáyàgbẹ̀
Ilé iṣé ìjọba tọ n mójú tó ọrọ ìlera àti di dènà àìsàn ni Orílè-èdè Nàìjíríà (NCDC) ti ṣe ìkìlọ fún àwọn ènìyàn àti àwọn eleto ìlera káàkiri nípa bí àìsàn Kábìkáyàgbẹ̀ tí tán ká ìpínlè mésàn àti ìjọba ibile ọgbọn.
Níbi jíjábọ̀ ohùn to…
Ilé iṣé MSF Tí Sí Ibùdó Ti Yóò Ma Já Fún Oúnjẹ Ti Ko péye
Ilé iṣé tó jẹ Medecins San Frontires (MSF) tí sí ibùdó tí yóò gba ibùsùn irínwó ni ìpínlẹ̀ kebbi láti dènà oúnjẹ ti ko péye to.
Ọgbẹni Higgins Maldonado to jẹ adarí ètò náà ni ìpínlẹ̀ Kebbi ló sọ èyí di mímọ̀ nígbà tí o n ba àwọn…
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Cross Rivers Se Òfin Tuntun Fún Ètò Ìlera
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Cross Rivers ti pààrọ̀ òfin ètò ìlera ti odún 2002 pẹ̀lú òfin tuntun ti ọdún 2025 lójúnà àti ní ìkóyawó àti ìkẹ́ṣẹjárí òfin ètò ìlera
Ọ̀gbẹ́ni Hillary Bisong, tí ó…
Ìjọba Ìpínlẹ Kaduna Àti Àjọ UNICEF Fọwọ́sowọ́pọ̀ Láti Gbógunti Àìsàn Ìgbóná
Ìjọba Ìpínlẹ Kaduna pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Àjọ UNICEF tí ń gbé ìgbésẹ̀ akin láti gbógunti ìtànkálẹ̀ àìsàn ìgbóná èyí tí ó ti sekúpa àwọn ọmọdé méjì ní Ìpínlẹ̀ Kaduna
Àìsàn náà, èyí tí ó…
Aṣòfin Oluremi Tinubu Pé Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Olori Ìlú Láti Fòpin Sí Dídá Abẹ Fún Ọmọbìnrin (FGM)
Àyà Ààrẹ Orilẹ Èdè Nàìjíríà, Aṣòfin Oluremi Tinubu ti ké sí àwọn Olórí ìlú àti agbègbè láti sa ipá wọn lójúnà àti fi òpin sí dídá abẹ fún ọmọ obìnrin (FGM), kòkòrò HIV/AIDS àti àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀.
Oluremi Tinubu lo fi ọ̀rọ̀ lédè lásìkò tó…
Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Fún Àwọn Arìnrìnàjò Hajj Fún Ọdún 2025 Ti Ìpínlẹ̀ Kwara Gbérasọ
Ìgbìmọ̀ Alálàájì ti Ìpínlẹ̀ Kwara bẹ̀rẹ̀ ètò abẹ́rẹ́ àjẹsára fún àwọn tí ó ń gbèrò láti se iṣẹ́ Hajj ti ọdún 2025
Nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ ìgbérasọ ètò náà ní Ìlú Ilọrin, Akọ̀wé ìgbìmọ̀…
Àjọ UNICEF Pè Fún Dídènà Àrùn Rọpá-rọsẹ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Kano
Àjọ UNICEF ti ké sí ìjọba Ìpínlẹ̀ Kano láti gbé ìgbésẹ̀ ní kíákíá lójúnà àti dènà àrùn rọ́pa-rọsẹ̀ látàrí bí àrùn náà se súyọ ní ìpínlẹ̀ Kano
Asojú Àjọ náà ní Ìpínlẹ̀ Kano, Rahma Farah ni ó…
Ìpínlẹ̀ Jigawa, Àjọ UNICEF Bẹ̀rẹ̀ Ìpolongo Abẹ́rẹ́ Àjẹsára
Ẹka Ètò Ìlera Ti Ìpínlẹ̀ Gigawa Pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Àjọ UNICEF ti gbáradì láti se ìfilọ́lẹ̀ ìpolongo abẹ́rẹ́ àjẹsára, èyí tí ìrètí wà pé àwọn ògo wẹẹrẹ tí kò dín ní mílíọ̀nù méjì ni yóò jẹ ànfààní…
Ìmọ́tótó Ni Ó Ń Ṣẹ́gun Àrùn Gbogbo- Ìjọba Ìpínlẹ̀ Jigawa Mú Ètò Ìmọ́tótó Ní…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gigawa, Malam Umar Namadi ti sàfirinlẹ ìgbáradì ìsèjọba rẹ̀ láti se ètò tí yóò mú kí àyíkà mọ́ tóní-tóní ní Ìpínlẹ̀ Gigawa
Gómìnà fi àrídájú náà léde nígbà tí àwọn ikọ̀…