Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Sokoto Se Ètò Ìlera Tí Ó péye Fún Ará Ìlú
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Sokoto ti fi àrídájú hàn pé gbogbo ènìyàn ìpínlẹ̀ náà ní yóò ní ànfààní ètò ìlera tí ó péye
Ọ̀gá àgbà fún àkóso ètò ìlera t́i ìpínlẹ̀ Sokoto, Mal Yusuf AbdulKarim ni ó sọ…
Ìpínlẹ̀ Oyo Pé Fún Ìbáṣepọ̀ Láti Dènà Àìsàn NTD
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Oyo ti pé fún ìbáṣepọ̀ àwọn tọrọ kàn láti dènà àìsàn tí wọn pè ní NTD, wọn ni ki àwọn yóò tún ṣe ibẹwo sí àwọn ilé ìwòsàn fún ọ̀nà abayọ.
Kọmísọ́nà fún ètò ìlera Dọ́kítà Oluwaserimi Ajetunmobi lo sọ èyí di mímọ nígbà tí o n…
Ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ Ebonyi Mary-Maudline N Ṣe Ikede Fún Àwọn Obìnrin Nípa Àìsàn Jẹjẹrẹ Ojú Ará .
Iyaafin Mary-Maudline Nwifuru ti bẹrẹ ìkéde nípa àìsàn jẹjẹrẹ ti ojú ará fún àwọn obìnrin ní ìpínlẹ̀ Ebonyi
Ilé ìwòsàn ìjọba ni Abakaliki ni ijoba ibile Enuwovu ni ìyàwó Gómìnà to ṣe ìkéde náà Lákòkóò ti o ṣe ìbẹ̀wò.
Àkọlé ti ọdún…
Orílẹ̀-èdè India Fi Ìdí Tó Fi Se Pàtàkì Láti Dókòwò Ní Ti Ọ̀rọ̀ Ìlera Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà…
Àjọ Nigeria-India Business Council (NIBC), India, ti so pé ó se pàtàkì fún wọn láti dókòwò ní ẹ̀ka ètò Ìlera pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Akọ̀wé àgbà patapata fún àjọ
NIBC, Rekha Sharma sọ eyi di mimo ni ibi iroyin lori afojusun…
Ibà Lassa Ṣúyọ Ní Ìlú Abuja, Àjọ Elétò Ìlera Sàwárí Ènìyàn Mẹ́rin
Alákòóso ẹka ètò ìlera ní ìlú Abuja, Dókítà Adedọlapọ Fasawa ti fi ọ̀rọ̀ léde nípa ìtànkálẹ̀ Ibà Lassa ní olú ìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Dókítà Fasawa sàlàyé nínú ìfọ̀rọ̀léde lórí ìsúyọ…
Ilé Ìwòsàn LASUTH Gbóríyìn Fún Àwọn òṣìṣẹ́ Méwàá Fún Àtìlẹyìn Wọn Nípa Ètò Ìlera.
Ilé ìwòsàn ijoba ìpínlẹ̀ Eko LASUTH ti gbóríyìn fún àwọn Òṣìṣẹ́ Méwàá ni ilé ìwòsàn náà, fún atilẹyin ati iṣẹ takuntakun wọn láti rí wí pé ìdàgbàsókè bá ilé ìwòsàn náà
Adari àgbà pátápátá fún ilẹ ìwòsàn LASUTH Ọ̀mọ̀wé Adetokunbo Fabamwo…
Ilé iṣé Aláàdáni Ṣe Àyẹ̀wò Ọ̀fẹ́ Nípa Ìlera Fún Àwọn Opó Àti Aláìsàn Fòní kú, Fọ̀la Dìde…
Ilé iṣé Aláàdàni lebarty Community Health Foundation, ṣe ayẹwo ọ̀fẹ́ nípa ìlera fún àwọn ènìyàn tó tó ogborun Márùn -ún opó ati awọn to ni àìsàn fòní kú, Fọ̀la dìde.
Àyẹwò yii waye ni agbègbè Aruogba ni ìpínlẹ̀ Edo.
Ọgbẹni Ezekiel…
Àjọ WHO Àti Ìpínlẹ̀ Anambra Wà Ní Ìbáṣepọ̀ Fún Ìtànkálẹ̀ Ètò Ìlera
Kọmísọ́nà ètò ìlera ìpínlẹ̀ Anambra, Dókítà Afam Obidike ti fi da àjọ WHO loju pé ipinle Anambra yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹlu àjọ World Health Organisation (WHO) fún ìlera pípé - Universal Health Coverage (UHC) jakejado ìpínlẹ̀ náà.…
Ààrùn ẹranko: Kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera kìlọ̀ fún ìbẹ́sílẹ̀ ní Cross River
Wọn ti rọ àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Cross River ní Gúsù Nàìjíríà láti jẹ́ kí ìmọ́tótó jẹ wọ́n lógún àti ìtún àyíká ṣe nítorí ìbẹ́sílẹ̀ ààrun ẹranko tí ó ti gbẹ̀mí ẹnìkan.
Kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera,…
Gombe kéde ìbẹ́sílẹ̀ ààrùn àwọn ẹranko
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Gombe ti kéde ìbẹ́sílẹ̀ ààrùn àwọn ẹranko ní ìpínlẹ̀ náà.
Kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera, Dókítà Habu Dahiru, sọ èyí lásìkò tí ó ń ṣàlàyé fún àwọn oníròyìn pé, arákùnrin aláárẹ̀ kan tí…