Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Ẹgbẹ́ Ṣe Ètò Àyẹ̀wò Fún Àwọn Ti Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìfipábánilòpọ̀ Ṣẹlẹ Sí Rí.

Ẹgbẹ́ ti wọn pè ní CSO àti ASSH Foundation ti ṣe ètò àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ fún àwọn ènìyàn tí ìṣẹ̀lẹ̀ ìfipábánilòpọ̀ ṣẹlẹ̀ sí rí fún àtúnṣe. Adari ètò náà Ọgbẹni Kingsley Yalling lo sọ èyí di mímọ nínú ìfòròwánilénuwò ní ọjọ́rú , Ó sọ wí pé àyẹwò…

Dí dènà Àìsàn Rọmọlápá: Àjọ UNICEF Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Gbọgán, Ọkọ̀ Tuntun Fún Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kebbi

Àjọ UNICEF ti ṣe Iranlọwọ gbọgán àti ọkọ̀ tuntun Ajọ́kẹ́lẹ́ merin fún ilé ìwòsàn ijoba ti ìpínlẹ̀ Kebbi. Nígbàtí o n sọ̀rọ̀ níbí ayẹyẹ náà  Gómìnà Nasir Idris  gbóríyìn fún Àjọ UNICEF fún ìrànlọ́wọ́ nla yìí eyi ti wọn ṣe fún ìpínlẹ̀ náà…
button