Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Àyájọ́ Àisìán Wárápá: Àjọ Ìlera Lágbayé Ṣe Àtìlẹ́yìn Láti Jẹ Kí Àwọn Ènìyàn Ni Ìmòye Nípa Àìsàn Naa.

Ni igbiyanju lati dẹkùn àìsàn wárápá àjọ àgbáyé fún ìlera bo síta fún ìkéde ìmòye lórí àìsàn náà fún ọdún 2024 Àkọlé ti ọdún yìí ni Àìsàn wárápá imọlẹ fún ìmòye lórí rẹ. Àjọ ìlera àgbáyé n gbìyànjú láti rí wí pé àwọn ènìyàn ni ìmòye…

Àwọn Tọ́rọ̀ kàn Fi Ẹ̀dùn Ọkàn Wọn Hàn Lórí Bi Àìsàn Ìfọ́jú Ṣé Ń Pósí Ní Ìpínlẹ̀ Plateau.

Àwọn tọrọ kàn ni ti ètò ìlera ni ìpínlẹ̀ Plateau tí fí ẹ̀dun ọkàn wọn hàn bi àisìán ojú fifọ ṣe n pósí ni náà to sì n jasi iṣẹ́ abẹ. Níbi Ìpàdé tí ẹgbẹ́ tó n mójú tó ọ̀rọ̀ ojú (RAAB) gbé kalẹ ní Jos ni àwọn tọrọ kàn ti sọ èyí jáde.…

Ó Se Pàtàkì Kí Òfin Tí Yóò Dènà Dídábẹ́ Fún Ọmọbìnrin Wáyé- Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Kan…

Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Dókítà Onímọ̀ Ìsègùn Òyìnbó, Nathaniel Adewọle ti Yunifásitì ìlú Abuja, Gwagwalada ti pè fún síṣe àgbékalẹ̀ òfin èyí tí yóò dènà dídábẹ́ fún àwọn ọmọdébìnrin ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà…
button