Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Ibà Lassa: Ìjọba Adamawa fìdí ẹnìkan tó ní ààrùn náà múlẹ̀, ẹ̀nìyàn mẹ́rin kò ní
Ìjọba Adamawa ti fìdí ẹnìkan tó ní ààrùn Iba Lassa múlẹ̀ nínú àwọn afurasí márùn ún tí wọ́n ti ní ní ìpínlẹ̀ náà.Kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera, Dókítà Felix Tangwami, sọ èyí níbi àpèjọ ìròyìn ní Yola, ní…
Àjọ Aláàánú Ọmọnìyàn Kan Pèsè Ohun Èlò Fún Àwọn Àkàndá Ẹ̀dá Ní Ìpínlẹ̀ Ọsun
Àjọ kan tí ó fi ìlú Osogbo se ibùjòkó ti pèsè kẹ̀kẹ́ mọ́kànlélàádọ́rin fún àwọn tí ó ní ìpèníjà ara ní ìjọba ìbílẹ̀ méjì tí ó wà ní ìlú Osogbo, àti fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ohun èlò náà wúlò fún…
Iṣẹ́ Àsekúdórógbó Léwu Fún Àwọn Elétò Ìlera- Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Sèkìlọ̀
Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nípa ìwádìí àìsàn Jẹjẹrẹ, Dókítà Ọmọlọla Salakọ ti sèkìlọ̀ nípa ewu tí ó wà níbi iṣẹ́ àsekúdórógbó fún àwọn elétò ìlera léyìí tí ó le è se àkóbá fún àlàáfíà ara wọn
Salakọ…
Àìsàn Yírùn-yírùn Gbalé-gboko Ní Ìpínlẹ̀ Jigawa
Alákòsóo ètò ìlera alábọ́dé ní ìpínlẹ̀ Jigawa, Dókítà Shehu Sambo ti sàfirinlẹ̀ ìsúyọ àìsàn yírùn-yírùn ní ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà ní ìpínlẹ̀ Jigawa
Ó fi ìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀ ní Dutse, ìpínlẹ̀…
Àìsàn jẹjẹrẹ: Ẹ rí Dájú wí Pé Àwọn Tó Kájú Òṣuwọn Ní Ò Ṣe Ìtọ́jú Àìsàn Jẹjẹrẹ: Atinuke.
Ilé iṣé tí wọn n pé ni Atinuke Cancer Foundation ti ro ìjọba àti àwọn Adari Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti rí wí pé àwọn tó Kájú Òṣuwọn ni o wa níbí ìṣàkóso ìtọjú àìsàn jẹjẹrẹ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Lásìkò ti wọn jáde fún ìtọjú àwọn ènìyàn ní…
Àìsàn Ọ̀fun Àti Imú: Ẹgbẹ́ Alágbèlébù pupa Ṣe Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Tọrọ kàn Lórí Àìsàn Náà.
Ẹgbẹ́ Alágbèlébù pupa ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ìpínlẹ̀ Yobe tí ṣe ìpàdé pàtàkì pẹ̀lú àwọn tọrọ kàn láti lee rí wí pé wọn ni ìmòye lórí àìsàn to n kọlù imu àti ọ̀fun.
Sabo Dagona, to jẹ òṣìṣẹ́ pàtàkì fún ìpínlẹ̀ náà, lo sọ èyí di mímọ ní…
Ẹgbẹ́ Aláàdáni Rọ Àwọn Obìnrin Láti Ṣe Ìtọ́jú Ara Wọn Dáradára.
Ẹgbẹ́ Aláàdáni kan to n mójú tó ìtọ́jú àwọn Obìnrin, ti Chick, Nneka Umuteme je Adari ẹgbẹ́ naa tí gba àwọn Obìnrin lámọ̀ràn láti rí wí pé wọn ṣe ìtọjú ará wọn daradara ṣáájú ohun kóhun.
Nínú ọ̀rọ̀ tó bá àwọn oníròyìn sọ ní o ti di mímọ,…
Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Pè Fún Àtúntò Ètò Ìlera Nípa Ìbára-Ẹni-Lòpọ̀ Ní Abala Ètò Ẹ̀kọ́…
Àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ ní ẹka ètò ìlera, ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti pè fún àtúntò tí ó peregedé ní abala ìbára-ẹni-lòpọ̀ àti ètò ìbímọ, èyí ti ó yẹ kí ó wáyé nínú ètò ẹ̀kọ́ ní àwọn ilé ìwé gíga…
Aya Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra Pèsè Àpò Ẹ̀fọn Àti Àwọn Ohun Èlò Ìlera Míràn Fún Àwọn…
Aya Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Arábìnrin Nonye Soludo ti pèsè àwọn ohun èlò ìlera fún àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ tí ó jẹ́ obìnrin ní Ameyi, Awka, níbi ìgbérasọ ìrìnàjò rẹ̀ sí àwọn ilé ẹ̀kọ́ gbogbo ní ìpínlẹ̀ náà…
Dọ́kítà Tó N Gbé Orílẹ̀-èdè US Fún Ilé Ìwòsàn Ijoba ABUTH Ni Malumfashi Ni Masini Àyẹ̀wò
Dọ́kítà Titus Okunlola,tí o fi Orílẹ̀-èdè USA ṣe ibùgbé tí pàṣẹ Masini Àyẹ̀wò fún ilé ìwòsàn ijoba Ahmadu Bello (ABUTH)ni Malumfashi, ni ìpínlẹ̀ Katsina.
Àwọn alákòóso ilé ìwòsàn náà ló jẹ kí èyí di mímọ, láti ẹnu ọrẹ pàtàkì rẹ Muhammad…