Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Ìjọba Àpapọ̀ Ṣetán Láti Dènà Àìsàn NTD.
Ìjọba Àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ wí pé àwọn ṣetán láti ṣe iranlọwọ fún dídènà àìsàn to wáyé nipa ẹfọn NTD èyí tí o n ṣe àkóbá fún àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Dọ́kítà Iziaq Salako tó jẹ Mínísítà fún ètò ìlera àti ìtọ́jú àwọn…
Ayé Dára Dé Ní Ìpínlẹ̀ Kwara: Sẹ́nétọ̀ Mustapha Se Ètò Ìlera Ọ̀fẹ́ Fún Àwọn Ènìyàn…
Ọmọ Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin tí ó ń sojú fún ààrin gbìngbìn Ìpínlẹ̀ Kwara ní ilé asòfin àgbà, Sẹ́nétọ̀ Saliu Mustapha ti se ìfilọ́lẹ̀ ètò ìlera ọ̀fẹ́ fún àwọn ènìyàn tí ó ń sojú fún, níbi tí àwọn ènìyàn…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Anambra Ti Gbé Ìgbésẹ̀ Ìfìyàjẹ Àwọn Òsìṣẹ́ Tí Ó Ń Se Ìmẹ́lẹ́ Lẹ́nu…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Anambra ti fi ìpinnu rẹ̀ hàn láti gbẹ́sẹ̀lé owó osù àwọn òsìṣẹ́ méjì tí ó jẹ́ ti ilé ìwòsàn alábọ́dé ti Abacha, èyí tí ó wà ní apá Arewa Idemili, látàrí pé wọ́n kùnà láti fi ara hàn lẹ́nu…
Àjàkálẹ̀ Àrùn Di Ohun Ìgbàgbé Ní Ìpínlẹ̀ Kebbi, Ìjọba Gba Àwọn Òsìṣẹ́ Elétò Ìlera…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kebbi ti kéde èròńgbà rẹ̀ láti gba òṣìṣẹ́ elétò ìlera ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta pẹ̀lú ìkúnlọ́wọ́ àwọn òsìsẹ́ ilé iṣẹ́ Global Alliance tí ó tó irinwó, èyí tí wọn yóò kópa nínú ètò abẹ́rẹ́ àjẹsára ní…
Ilé Ìtajà Di Títìpa Ní Ìpínlẹ̀ Kaduna Látàrí Ọjà Tí Ó Ti Bàjẹ́
Àjọ NAFDAC gbé ìgbésẹ̀ akin pẹ̀lú títi ilé ìpa-ọjà-mọ́ kan pa látàrí àwọn oúnjẹ àti ohun èlò míràn tí ó ti bàjẹ́, èyí tí ó tó mílíọ̀nù márùn-ún dín-lọ́gọ́rin náírà ní ìlú Kaduna
Shaba Muhammed…
Ọ̀pọ̀ Àwọn Ènìyàn Ni Yóò Jẹ Anfààní Ìtọ́jú Ọ̀fẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Eko
Ó kéré tàn àwọn ènìyàn tó lẹ́ ni ọgọrun àti àádọta ni yóò jẹ anfààní ètò ẹkọ ọfẹ ni ìpínlẹ̀ Èkó, pàápàá jùlọ ní ijoba ìbílẹ̀ Surelere .
Wọn ní àwọn ènìyàn ti wọn ti fi orúkọ sílẹ̀ tí le ni ọgọrùn ni ile ìwòsan ìjọba.
Ilé ìwòsan ìjọba…
Ẹ Dẹkun ìwà Ọkùnrin Jù Obìnrin Lo Ni Ìpínlẹ̀ Enugu: ilé iṣé Aláàdáni.
Ilé iṣé Aláàdáni tí nṣe Ìrànlọ́wọ́ fún àwọn Obìnrin tí kéde wí pé àwọn yóò bèrè sí ni Dẹkun ìwà Ọkùnrin Jù Obìnrin èyí tí ko fi àye gbà àwọn obìnrin lati rówó mú ni ìpínlẹ̀ Enugu.
Adarí àgbà fún ilẹ isé náà, iyaafin Amala Nweke ló sọ…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Imo Fọ̀wọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àjọ NDLEA, Ọlọ́pàá Láti Fí Òpin Sí Ìwà Àsìlò…
Ìjọba ìpínlẹ̀ Imo ti fi ìgbáradì rẹ hàn láti fi ọwọ́ sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn àjọ tí ọ̀rọ̀ kàn lójúnà àti fi òpin sí ìwà àsìlò ògùn èyí tí yóò jẹ́ kí ó di ohun àfìsẹ́yìn tí egúngún ń fi aṣọ láwùjọ…
Ètò Ìfètòsọ́mọbíbí A Máa Jékí Ọmọ Dàgbà Dáradára -Àjọ AAFP
Alága àjọ Association for the Advancement of Family Planning (AAFP) ni Nàìjíríà, Dókítà Ejike Oji ti sọ pe ètò Ìfètòsọ́mọbíbí a máa jeki Ọmọ dàgbà dáradára, a máa dènà ọmọ rándanràndan.
Ọ̀gbẹ́ni Oji sọ eyi nibi…
Ẹgbẹ́ OYSHMB Bèrè Fún Àtúnṣe Lórí Àwọn Ilé Ìwòsàn Ìjọba Ni Ọdún 2025.
Alága fún àwọn ilé ìwòsan ni ìpínlẹ̀ Oyo (OYSHMB), Dọ́kítà Akin Fagbemi ti jẹ ko di mímọ wí pé àwọn yóò ṣe àtúnṣe ṣe lórí àwọn ilé ìwòsan ìjọba káàkiri, pàápàá jùlọ ló ní ètò ọmọ bíbí
Fagbemi sọ èyí di mímọ̀ nígbà tí o ṣe ìkíni e ku…