Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀pọ̀ Àwọn Ènìyàn Ni Yóò Jẹ Anfààní Ìtọ́jú Ọ̀fẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Eko

67

Ó kéré tàn àwọn ènìyàn tó lẹ́ ni ọgọrun àti àádọta ni yóò jẹ anfààní ètò ẹkọ ọfẹ ni ìpínlẹ̀ Èkó, pàápàá jùlọ ní ijoba ìbílẹ̀ Surelere .

Wọn ní àwọn ènìyàn ti wọn ti fi orúkọ sílẹ̀ tí le ni ọgọrùn ni ile ìwòsan ìjọba.

Ilé ìwòsan ìjọba ìbílẹ̀ Akerele àti ilé iṣé ìjọba ìpínlẹ̀ Eko LASHMA ní wọn ṣe alagbateru ètò náà.

Ọgbẹni Ayodele Jeje- Odion gbóríyìn fún ìjọba látàrí bi wọn fi ìtọjú àwọn ènìyàn ṣọkan láti ṣe ìtọjú àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà.

Ó ni èyí jẹ àfihàn wí pé ìtọjú àwọn ènìyàn ṣe pàtàkì nitori ọpọ àwọn ènìyàn ni kò ni àgbàrá láti ṣe ìtọjú ará wọn.

Comments are closed.

button