Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Ilé-Iṣẹ́ Ìlera Nàìjíríà Tí Ṣé Ìlànà Láti Fòpin Sí Ìyanṣẹ́lódì Tí Ẹgbẹ́ JOHESU

Ilé-Iṣẹ́ Ìlera Àpapọ̀ àti Àlàáfíà Àwùjọ ti Nàìjíríà tún sọ ìpinnu Ìjọba Nàìjíríà láti mú ìṣọ̀kan ilé-iṣẹ́ náà dúró ní ẹ̀ka ìlera, bí wọ́n ti kéde ìlànà láti yanjú ìyanṣẹ́lódì ìṣòwò pẹ̀lú Àwọn Ẹgbẹ́ Ìlera Àpapọ̀ (JOHESU). ‎ ‎ Nínú…

Àyà Ààrẹ Orilẹ Èdè Nàìjíríà, Aṣòfin Oluremi Tinubu ti ké sí àwọn Olórí ìlú àti agbègbè láti sa ipá wọn lójúnà àti fi òpin sí dídá abẹ fún ọmọ obìnrin (FGM), kòkòrò HIV/AIDS àti àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀. Oluremi Tinubu lo fi ọ̀rọ̀ lédè lásìkò tó…

Àwọn Dókítà bèèrè fún ìgbàpadà àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn tí wọ́n dá dúró lẹ́nu iṣẹ́

Ikọ̀ Àringbùngbùn –Àrewa ti Ẹgbẹ́ àwọn Àgbàa Dókítà (ARD), ti panupọ̀ béèrè fún gbígbà padà àwọn ẹlegbẹ́ wọn tí wọ́n dá dúró lẹ́nu iṣẹ́ ní Ilé Ìwòsàn Olùkọ́ni tìjọba àpapọ̀ (FTH), ti Lokoja, ní ìpínlẹ̀ Kogi,…
button