Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
This is a category for entertainment news
Akọrin Ọmọ Nàìjíríà, Tems TaYọ Kọjá Rihanna Àti Beyonce Nínú Àte US Billboard Tuntun
Akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè ti fi ìtàn balẹ̀ nínú àtẹ US Billboard ti orin ju Olùkọrin Obinrin ti orílẹ-èdè Amerika, ògbóǹtarìgì bíi Rihanna àti Beyonce.
Ọ̀gbóǹtarìgì ọmọ Nàìjíríà tó ti gba àmì ẹ̀yẹ orin ni ìgbà kan ri ti lù aluyọ̀ ní àkọ́lé…
Alásè Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Hilda Baci ti gba ife àgbáyé Guiness World Record
Alásè Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà kan, Hilda Effiong Bassey ti gbogbo ayé mọ si Hilda Baci ti di ẹni to ṣe ounje fun wakati to pọ ju lọ ni gbogbo agbaye ni àárọ̀ oni ọjọ kẹẹdogun, ọjọ ajé oṣu karun-un, ọdun 2023, o si dana fún ọgọrin meje wakati…
Tinubu Sàtìlẹyìn Fún Hilda Láti Gba Oyè Alásè Oúnjẹ Jùlọ Ní Àgbáyé
Ààrẹ tí wọ́n dìbò yàn, Bọla Ahmed Tinubu ti lu ìlù gbọ-in gbọ-in ni a wà lẹ́yìn rẹ fún Hilda Baci, nígbà tí ó setán láti gba àmì ẹ̀yẹ àgbáyé ẹni tí ó le è dáná oúnjẹ jùlọ.
Láti gba àmì ẹ̀yẹ…
Kizz Daniel Fi Àwo Orin Tuntun Aládùn Léde
Gbajúgbajà akọrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti fi àwo orin tuntun léde tí gbogbo ayé sì gbà á yẹ̀wò, èyí tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní “Shu Peru”.
Àwo orin náà jẹ́ eléyìí tí kò lẹ́gbẹ́, tí ó sí jẹ̀ etí ní…
Fídíò Kan, Mílíọ̀nù Kan Dọ́là Ni- TG Omori
Gbajúgbajà olùtẹ orin àti àwọn àwòrán jáde lórí Fídíò nì ThankGod Omori Jesam, tí ìnangi rẹ̀ ń jẹ́ TG Omori tàbí 'Boy Director,' ti sọ èròngbà rẹ̀ láti sún oye owó tó ń gbà lọ́wọ́ àwọn ènìyàn lọ sí Dọ́là kan Mílíọ̀nù fún àtẹ̀jáde…
Olórin Tó Tún Jẹ́ Òṣèré Ọmọ Nàìjíríà, Ọ̀gbẹ́ni Falz Bẹ̀bẹ̀ Fún Àdúrà Lẹ́yìn Iṣẹ́ Abẹ
Ọmọ Nàìjíríà Olórin tó tún jẹ́ òṣèré, Folarin Falana tí wọ́n ń pè ní Falz ti bẹ̀bẹ̀ fún àdúrà àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yìí lẹ́yìn Isẹ́ abẹ tó se.
Ó sọ èyí nípasẹ̀ Fídíò tó gbé jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára Instagram wipe " nǹkan tí òun ń…
Akọrin Davido Se Àjọyọ̀ Ọdún Méjìlá Tó Gbé Àwo Orin Rẹ̀ Àkọ́kọ́ Jáde
Olùkọrin 'afrobeats' , Davido ń se àjoyọ̀ ọdún méjìlá tó gbé àwo orin rẹ̀ àkọkọ jáde, tó pè ní "Back When". Orin náà se àfihàn Naeto C. Ni ibi orin náà ló ti kọ́kọ́ lù àlùyọ.
Ọdún Kejìlá sẹ́yìn nìyi tó ti gbé orin…
Gbajú-gbajà Eléré Ìtàgé Eniọla Badmus Ní Alága Àwọn Olùgbàlejò Fún Ayẹyẹ Ètò Ìbúra…
Gbajúmọ̀ Eléré Ìtàgé, Ẹniọla Badmus ni wọ́n ti yàn gẹ́gẹ́ bí alága àwọn olùgbàlejò fún ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ ìjọba tuntun Ààrẹ tí wọ́n dìbò yàn, Bọla Ahmed Tinubu
Síwájú ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n osù…
Ìgbà Ọ̀tun Wọlé Ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà Ẹ Máa Jó Jàgínní Yòdò – Toyi Abraham
Gbajúgbajà eléré orí ìtàgé, Toyin Abraham ti fi àrídájú hàn pé ìgbà ọ̀tun ti dé bá Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde lórí ẹ̀rọ abẹ́yẹfò rẹ̀ ní ọjọ́ Àbámẹ́ta nígbà tí ó sọ pé…
”Ipò bàbá mú mi fòpin sí àwọn ìwà pálapàla” –Zlatan Ibile
Akọrin Nàìjíríà, Omoniyi Temidayo Raphael, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Zlatan Ibile, ti ṣíṣọ lójú àwọn àṣeyọrí rẹ̀ méjì tó ga jù láyé.
Zlatan sọ pé ipa òun bíi bàbá àti orin òun ti yí àwọn nǹkan tó pọ̀ padà lára…