Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Àwọn Aṣòfin Nàìjíríà Yóò Tẹ̀síwájú Nínú Àjọṣepọ̀ Ìdàgbàsókè Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Kenya

Ilè Ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣofin yóò tẹ̀síwájú nínú àjọṣepọ̀ wọ́n pẹ̀lú Kenya lórí ìdàgbàsókè àwọn apá pàtàkì tí ètò-ọrọ àjé. ‎ ‎ Alága, Ẹgbẹ́ Ilé aṣòfin Orílẹ̀-èdè méjèèjì, Ọ̀gbẹ́ni Abdullahi El-rasheed, fúnni ní ìtọ́kasí ní ìpàdé kán pẹ̀lú…

Ilé iṣẹ́ ìjọba tí ń rísí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin yóò ṣàgbékalẹ̀ ìlànà ilé ìfowópamọ́…

Ilé iṣẹ́ ìjọba tí ń rísí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin ní Nàìjíríà yóò ṣàgbékalẹ̀ ìlànà ilé ìfowópamọ́ alábọ́ọ́dé lórílẹ̀-èdè fún àwọn olùṣòwò jákèjádò Nàìjíríà. Minisita fun ọrọ awọn obinrin, Imaan…

Ìgbìmọ̀ Ìjọba Àpapọ̀ Buwọ́lu Ogún Bílíọ̀nù láti Ra Ohun Èlò Fún Àjọ Tí Ó Ń Sàyẹ̀wò…

Ìgbìmọ̀ Ìjọba Àpapọ̀ ti buwọ́lu ogún bílíọ̀nù náírà láti ra àwọn ọkọ̀ tí ó ń lo afẹ́fẹ́ gáàsì àti àwọn ohun èlò míràn fún àjọ tí ó ń sàyẹ̀wò ẹrù àti àwọn ohun èlò gbogbo ( Nigeria Custom Service) àti…

Òsìṣẹ́ Iná Mọ̀nàmọ́ná Fí Àáké Kọ́rí Ní Ìpínlẹ̀ Kaduna látàrí Dída Òsìṣẹ́ Sílẹ̀…

Ẹgbẹ́ Òsìṣẹ́ Iná Mọ̀nàmọ́ná ti gúnlé ìyanṣẹ́lódì ní Ìpínlẹ̀ Kaduna látàrí bí Ilé Iṣẹ́ tí ó ń pín iná mọ̀nà-mọ́ná se fi èròńgbà rẹ̀ léde láti da àwọn òsìṣẹ́ tí ó tó ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún sílẹ̀   Ilé…

Ìpínlẹ̀ Kwara Wà Lókè Té-ń-té Nípa Mímú Ìgbòòrò Bá Ọjà Ohun Ọ̀gbìn ní Ẹṣẹ̀ Kùkú

Báńkì Àgbáyé ti gbósùbà fún Ìpínlẹ̀ Kwara nípa àtìlẹyìn rẹ̀, tí ó sì tún jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ ní Orílẹ̀-èdè tí ó mú ìdàgbàsókè ọjà ohun ọ̀gbìn ní ọ̀kúkúdùn pẹ̀lú pípèsè owó àti ohun èlò tí ó…

Nàìjíríà Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ibùdó Ìtajà Fáàárí Ńlá Ni Borno L’ójúnà Látí Pèsè Iṣẹ́ ‎

Ìjọba Nàìjíríà tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ọjà fáàárí nlá kán ni Maiduguri, Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Borno, pẹ̀lú afojusun látí pèsè iṣẹ́ tó fẹ́ tó ẹgbẹ̀rún àádọ́ta nípasẹ ilé-iṣẹ́ náà. ‎ ‎ Ní ìtẹ̀síwájú àtìlẹ́yìn tí oní bílíọ̀nù márùn-dín-lọgọ́rin (N75b)…
button