Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Orílẹ̀-èdè Gabon Yóò Dìbò Ààrẹ Àkọ́kọ́ Lẹyin Ìfipágbàjọba Ológun Ọdún 2023
Orílè-èdè Gabon Yoo di Ibo ààrẹ àkọkọ rẹ ni ọjó Àbámẹ́ta lẹyin ọdún méjì ìdìtẹ̀gbàjọba tó wáyé ní orile-ede náà. Èyí yóò sàmìn sí ìgbéjọba padà fún alágbádá.
Ibùdó idibo tó le ní Ẹgbẹrun mẹta ní wọ́n ti pèsè ni…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè South Sudan Yọ Mínísítà Fún Ilẹ̀ Òkèèrè Nípò
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè South Sudan, Salva Kiir ti yọ Minisita Ilẹ̀ Òkèèrè, Ramadan Mohamed nípò, ó yan igbákejì rẹ̀ Monday Simaya Kumba gẹ́gẹ́ bí mínísítà tuntun fún ilẹ̀ òkèèrè èyí tí ó wáyé ní Ọjọ́rú
Kò…
DR Congo: Omíyalé Agbára Ya Gboro Pa Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n Ènìyàn
Omi àgbàrá Òjò ti pa Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n olùgbé, ó sì tún gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé lọ ni Kinshasa ti ṣe Olú ìlú Congo.
Bí Mínísítà òde orílẹ̀-èdè ṣe sọ, àwọn tó lùgbàdí ọ̀ràn náà ni àgbàrá Òjò àrọ̀rọ̀rọ̀dá sekúpa, tó sì gbélé lọ ti…
Akitiyan Àjọ UN Láti Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Ní South Sudan Ń Tẹ̀síwájú
Bí awuye-wuye, ìdààmú dààbo àti wàhálà ti ó n sẹlẹ̀ ní South Sudan kò se tí ì fi ara rọ, ni àjọ UN náà kò kùnà nínú ojúse rẹ̀ láti rí i dájú pé alaafia jọba ní àgbègbè náà tí àwọn ọmọ ogun àjọ náà…
Ìgbòkègbodò àti àjàkálẹ̀ ààrùn kojú DR Congo
Ilé iṣẹ́ UN fún àbujútó ọ̀rọ̀ Ìṣàànú (OCHA), ti ké gbàjarì lórí bí àìláábò ṣe ń pọ̀ si ní Arewa àti Gusu Kivu lórílẹ̀-èdè Congo (DRC), níbi tí ìwà ipá ti tẹ̀sìwájú láti máa fa ìṣubú, ìpalára fún…
Ìwọ́de Ọdún 2021-24: Orílẹ̀-èdè Sénégal Buwọ́lù Àtúngbéyẹ̀wò Òfin Ìforíjì
Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílè-èdè Senegal ti buwọ́lù àtúngbéyẹ̀wò òfin ìforíjì ti iwọ́de ọdún 2021 sì ọdún 2024 sì wà ninú rẹ, èyí la ọnà abayọ fún ìdájọ fún ẹgbẹlẹmùkú àwọn ènìyàn tó kú níbi ìwọ́de.
Òfin náà ní wọn gbà…
Eid Al-Fitr Ní Goma: Ìpè Fún Ìṣọ̀kan Àti Àlàáfíà
Ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ènìyàn péjọ sì ìlú Goma ní ọjọ́ Àìkú àná láti yayọ̀ ọdún ìtunu ààwẹ̀ - Eid Ali Fitr, tó sàmìn sí òpin oṣù mímọ́ ti Ramadan.
Fún àwọn Mùsùlùmí ní ìlú nlá yìí tó wà lábẹ́ ìsàkóso ikọ̀ Ọlọ̀tẹ̀ M23, ọjọ́ náà jẹ́…
Ọmọ Ogun Afipagbajọba Kéde Ijọba Ọdún Márùn-ún Ìṣèjọba Alágbádá
Ìjọba Ologun Ile Niger ti kéde ọdún márún idajọba padà sọ́wọ́ ijọba alagbada ti òfin la kalẹ láti ọjọ́ Ọjọ́rú gẹgẹ bí òfin iyipada tuntun ti wọ́n sẹ̀sẹ̀ buwọ́lù.
Ikede yìí tẹ̀lé ètò ìdìtẹ̀gbàjọba ọdún 2023 tó sì ààrẹ…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Namibia Yan Alákòso Iṣẹ́ Àti Ìsòwò
Ààrẹ Tuntun Fún Orílẹ̀-èdè Namibia tí wọ́n dìbò yàn, Netunbo Nandi-Ndaitwah ti kéde Ericah Shafudah ní ọjọ́ Àbámẹ́ta gẹ́gẹ́ bí Alákòso Isẹ́ àti Ìsòwò pẹ̀lú ojúgbà rẹ̀ Lucia Witbooi gẹ́gẹ́ bí igbákejì Ààrẹ…
Ológun Gbàjọba Olú Ilé Ise Ilé Ìfowópamọ́ Àgbà Orílẹ̀-èdè Sudan
Àwọn ọmọ ológun ilẹ̀ Sudan ti gbàsàkóso olu ilé iṣẹ Ilẹ́ Ìfowópamọ́ àgbà Orílẹ̀-èdè Sudan, ologun meji sọ èyí fún oníròyìn ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, eyi tii ṣe igbese nla míràn pataki ìtèsíwájú ogún lòdì si àwọn ikọ̀
paramilitary Rapid…