Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Ààrẹ Tshisekedi Ti Orílẹ̀-èdè DR Congo Se Ìwọ́de Ìpolongo Àsekágbá Síwájú Ètò…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè DR Congo, Felix Tshisekedi ti se ìpolongo àsekágbá síwájú ìdìbò gbogbogbòò tí yóò wáyé ní Ọjọ́rú, lójúnà àti fún-un ní ànfààní láti padà sí orí àlééfà gẹ́gẹ́ bí ààrẹ Orílẹ̀-èdè…
Orílẹ̀-èdè Kenya Àti European Union Yóò Ni Ìbáṣepọ̀ Tó Dan Mọ́rán Láti Mu Ìlọsíwájú Ba Ètò ọ̀rọ̀…
Orílẹ̀-èdè Kenya ati Orílẹ̀-èdè European Union ni Ìbáṣepọ̀ tó dàn mọ́rán láti mú ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú bá ètò ọ̀rọ̀ ajé, ni ọjọ́ ajé ni ọ̀rọ̀ náà di mímọ̀
Orílẹ̀-èdè méjèjì jọ fi enu kò sí inú oṣù keje lẹyìn ìpàdé.
Orílẹ̀-èdè EU jẹ…
Somalia Fọ́wọ́ Sí Ìwé Àdéhùn Látí Darapọ̀ Mọ́ Àgbègbè Ìlà-oòrùn Áfíríkà
Orílẹ̀-èdè Somalia ní wọ́n tí gbá wọlé gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ kẹjọ tí àgbègbè Ìlà-oòrùn Áfíríkà (East African Community EAC), lẹyìn ọsẹ kẹta ti wọ́n gbá wọlé nínú ìpàdé àwọn Olùdarí kàn ní Arusha, Tanzania.
Ààrẹ Hassan Sheikh Mohamud…
Ìgbésẹ̀ Ìdìtẹ̀-gbàjọba Wáyé Ní Orílẹ̀-èdè Sierra Leone- Ààrẹ Julius Maada Fi…
Nínú ìkéde tí Ààrẹ Julius Maada Bio ti Orílẹ̀-èdè Sierra Leone se, Ó fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé ìgbésẹ̀ ìdìtẹ̀-gbàjọba ni o ́wáyé ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n osù kọkànlá
Ààrẹ sàlàyé pẹ̀lú àbájáde…
Ènìyàn Ogún Nínú Àwọn Tí Ó Fi Arapa Ní Ìlú Gaza Gba Ìtọ́jú Ní Orílẹ̀-èdè Tinisia
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Tunisia sàlàyé pé oun ti se ìtọ́jú àwọn ènìyàn tí ó fi arapa ní ìlu Gaza níbi tí wàhálà ti ń sẹlẹ̀ láàrin Hamas àti àwọn ọmọ Ogun Isreal nígbà tí wàhálà náà tún gbérasọ lẹ́yìn ìgbà…
Àwọn Mínísítà Áfíríkà fún ọ̀rọ̀ òkèèrè mẹ́ta gbìmọ̀ àjọṣepọ̀
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ òkèèrè ti Burkina Faso, Guinea àti Mali, tí ológun ń ṣe ìjọba rẹ̀, ti gbìmọ̀ àjọṣepọ̀ tí yóò pèsè káràkátà àti ìkojú àìláábò ní agbègbè, wọ́n sọ èyí gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rọ̀ àjọsọ nígbà…
COP28: Ààrẹ Pè fún ìnáwó tó tọ́ láti ran àwọn orílẹ̀-èdè tó ní ìpalára lọ́wọ́.
Ààrẹ orílẹ̀-èdè South Africa ti rọ àwọn adarí lágbàáyé , tí wọ́n kórajọ fún COP28, láti ran àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kojú ìpalára làásìgbò ojú ọjọ́ lọ́nà tó pọ̀ ju bó ṣe yẹ lọ.
Ninu itan, awọn orilẹ-ede to n…
Iró Ìbọn Ń Dún Kíkàn Mọ́jú Ní Olú-ìlú Orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau
Iró ìbọn ń dún kíkàn kíkàn látí òru Ọjọ́bọ̀ tí tí dì òwúrọ̀ ọjọ́ Ẹtì ní Olú-ìlú Orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau.
Ìdí tí ìbọn ṣé ń dún kó yé ẹnìkán.
Ìròyìn kan sọ pé ìbọn ni a kọ́kọ́ gbọ́ lẹ́yìn ọ̀gànjọ́ òru ní àdúgbò Antula, ní ẹ̀yìn odi…
ECOWAS ṣetán láti gbé ìgbésẹ̀ lórí àtìmọ́lé Mohamed Bazoum
Àjọ tó ń mójútó ètò ọrọ̀ ajé orílẹ̀-èdè Iwọ̀-oòrùn Adúláwọ̀ ,(ECOWAS) ti ṣetán láti gbé ìgbésẹ̀ lórí ẹjọ́ tí wọ́n gbé kalẹ̀ fún àwọn agbẹjọ́rò ààrẹ orílẹ̀-èdè Niger tẹ́lẹ̀, Mohamed Bazoum lóríi bí wọ́n ṣe…
Goda Tí Egypt Fí Ará Rẹ̀ Ṣé Àpẹẹrẹ Fún Ìkọ Rẹ̀ Nínú Ìdíje ‘ITTF World Youth Championships…
Ìrawọ àgbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́yìn lórí tábìlì ọmọ Orílẹ̀-èdè Egypt Hana Goda ló lè iwájú fún àwọn àkẹ́gbẹ́ rẹ̀ bò ṣé bóri àwọn oludije láti Orílẹ̀-èdè Slovenia pẹ̀lú àmì ayò mẹ́ta sí ọkàn (3-1) nígbà Kejì nínú ìdíje 'ITTF World Youth Championships…