Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Arábìnrin Asantewaa Ṣètò Látí Fí Ìtàn Balẹ̀ Nínú Ìwé ‘Guinness World Record’
Arábìnrin ọmọ Orílẹ̀-èdè Ghana kàn, Afua Asantewaa Aduonum tí wà lórí ìrìn-àjò láti fi orúkọ rẹ̀ sínú ìwé Àgbáyé 'Guinness World Record' fún ìdíje eré orin tó pẹ́ jùlọ.
Nínú ìgbìyànjú rẹ̀ látí fí orúkọ rẹ̀ parọ tí Sunil Waghmare ọmọ…
Angola yóò dágb́ere fún OPEC, ọmọ ẹgbẹ́ dín ku orílẹ̀-èdè méjìllá
Angola ti sọ pé òun ń dágbére fún Àjọ orílẹ̀-èdè tí ń ta epo ilẹ̀ sí orílẹ̀-èdè mìíràn (OPEC), láti ọjọ́ kìnníí, oṣù kínníí ọdún 2024, lẹ́yìn tí ó kúrò ní Ecuador ní 2020 àti Qatar ní 2019.
Angola,…
Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-èdè Senegal Sọ Dakar Mayor Sí Ẹ̀wọ̀n
Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-èdè Senegal ti fi Mayor Dakar sí ẹ̀wọ̀n látàrí jíjẹ̀bi ẹ̀sùn ìsekúpànìyàn tí ó wáyé lásìkò rògbòdìyàn òsèlú ọdún 2011
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Barthelemy Dias tí ó jẹ́ alátakò…
Orílẹ̀-èdè Morocco Ní Ìpèníjà Ọ̀dá Òjò Fún Ìgbà Ẹlẹ́ẹ̀kẹfà- Mínísítà Ètò…
Orílẹ̀-èdè Morocco tí ó mú ètò ọ̀gbìn ní ọ̀kúkúdùn ti ní ìpèníjà ọ̀dá òjò fún ìgbà ẹlẹ́ẹ̀kẹfà latari àdíkù tí ó débá òjò tí ó rọ̀ fún osù díẹ̀ sẹ́yìn láti ara àyípadà ojú ọjọ́ tí ó wáyé…
France Tí Ìlẹ̀kùn Ilé-iṣẹ́ Aṣojú Rẹ̀ Ní Niger
France tí pinnu láti tíì Ilé-iṣẹ́ Aṣojú rẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Niger, "níbití kò sí ànfààní látí ṣiṣẹ́ déédéé, bó tí tọ́ àti bó tí yẹ́," ní ìbámu sí ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ náà, òun tó dájú ní ìpínyà láàrin Orílẹ̀-èdè méjèèjì
Èyí ló wáyé lẹyìn tí…
Angola Kéde Látí Kúrò Gẹ́gẹ́ Bí Ọmọ Ẹgbẹ́ OPEC
Angola tí kéde pé oún tí kúrò l'ára ọmọ ẹgbẹ́ OPEC, èyí ló wáyé lẹyìn ìdá Ifọ́po kékeré tí wọ́n fún orílẹ̀-èdè náà tí kò sí bá wọ́n lára mú.
Diamantino de Azevedo, tó jẹ́ Mínísítà èpò rọbi tí orílẹ̀-èdè náà, sọ pé Angola “kó lè jèrè…
Faransé sọ dókítà Rwanda tẹ́lẹ̀ rí sí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlé-lógún fún pípa ìran kan run
Dókítà Rwandan kan tẹ́lẹ̀ rí ti fi ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlé-lógún gbára láti ilé ẹjọ́ Faransé fún ìlọ́wọ́sí ìparun ìran kan ní ọdún 1994.
Sosthene Munyemana jẹbi ipaniyan run, ni Ọjọru, iwa buruku si ọmọniyan ati ikopa…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Egypt Se Ìfiléde Ọ̀rọ̀ Ìjáwé Olúborí Rẹ̀
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Egypt, Abdel Fattah Al-Sisi ti jáwé olúborí fún sá à ẹlẹ́ẹ̀kẹta pẹ̀lú rírí ìbò tí ó pọ̀ jùlọ nínú ètò ìdìbò tí ó wáyé ní Orílẹ̀-èdè náà. Àjọ elétò ìdìbò ni ó kéde ìjáwé…
Olórí Adìtẹ̀gbàjọba Se Àtúntò Àwọn Òsìṣẹ́ Ẹka Ìjọba Ní Orílẹ̀-èdè Burkina Faso
Olórí Adìtẹ̀gbàjọba ní Orílẹ̀-èdè Burkina Faso, Ọ̀gágun Ibrahim Traore, ẹni tí ó gun orí àlééfà ní ọdún 2022 ti se àtúntò àwọn adarí ẹka ìjọba èyí tí ó se pàtàkì fún ìkẹ́ṣejárí àkóso ìjọba rẹ̀
…
Ààrẹ Tshisekedi Ti Orílẹ̀-èdè DR Congo Se Ìwọ́de Ìpolongo Àsekágbá Síwájú Ètò…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè DR Congo, Felix Tshisekedi ti se ìpolongo àsekágbá síwájú ìdìbò gbogbogbòò tí yóò wáyé ní Ọjọ́rú, lójúnà àti fún-un ní ànfààní láti padà sí orí àlééfà gẹ́gẹ́ bí ààrẹ Orílẹ̀-èdè…