Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Super Eagles Tiraka Láti Fi Ìyà Tótó Jẹ Guinea Bissau Pẹ̀lú Àmì Ayò Kan Sódo (1-0) – Kí Wọ́n…
Super Eagles àti Guinea Bissau bẹrẹ ere bọọlu yii ni dede ago mẹfa irọlẹ oni, onikaluku wọn fi gbogbo agbara ti wọn ni daabo bo àwọ̀n wọn.
Ikọ Agbabọọlu Guinea Bissau ti gbiyanju lati mi àwọ̀n Super Eagles ni bíi ogun isẹju ti wọn bẹrẹ…
Ẹlọ Fọkànbalẹ̀ Ẹ̀yin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà, Àlù Bami Ni A Ó Na G’Bissau –…
Gẹ́gẹ́ bí ẹ ṣe mọ̀ pé máàkì mẹrin laní ní ori tabili wa, ti a si tún wa ni ipo keji, nigba ti Equatorial Guinea wa ni ipo kinni pẹ̀lú anfaani goolu ti wọn ni ju wa lọ, a ni igboya pe, a o bọ si ipo kinni lẹyin ti a ba kojú Guinea…
Aarẹ Egypt Ṣèlérí Ààbò Fún Somalia Lórí Èyíkéyìí Ẹrù
Ààrẹ Egypt Abdel Fattah el-Sissi sọ pé Orílẹ̀-èdè rẹ̀ tí ṣetán láti dáàbòbo Somalia lórí èyíkéyìí irọkẹ̀kẹ ẹrù, èyí tí wọ́n ṣàpèjúwe bí ìdáhùn sí ìgbésẹ̀ tí Orílẹ̀-èdè Ethiopia gbé láìpẹ́ yìí látí wọlé sí ibùdó omí tí Somalia.
Sissi ṣé…
Wọ́n Ṣé Ìbura Sáà Kéjì Fún Ààrẹ Congo Felix Tshisekedi
Ààrẹ Congo Felix Tshisekedi ní wọ́n tí búra fún ní Ọjọ́ Àbámẹ́ta, ogúnjọ́, Oṣù Kínní, ọdún 2024 lẹyìn ìdìbò gbogbogbò tí Oṣù Kejìlá ọdún tó kọjá, pẹ̀lú ìlérí látí fí ìsọkan rínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè náà ní sáà Kéjì tí ọdún márùn ùn rẹ̀ àtí látí…
Salah Kòní Kópa Nínú Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ AFCON Méjì Látàrí ìfarapa
Ẹlẹ́ṣẹ̀ ayò ọmọ Egypt, Mohamed Salah yóò padanu ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Africa Cup of Nations (AFCON) méjì látàrí ìfarapa ẹsẹ to wáyé ni ọjọ Ọjọ́bọ̀ níbi ti ikọ̀ rẹ̀ ti parí pẹlu ayò méjì méjì (2-2) pẹ̀lú Ikọ̀ Ghana ni ìlú Abidjan, àjọ…
Orílẹ̀-èdè Kenya Kéde Ìfopin Ṣí G20 Ìpèsè Àdéhùn Elépo
Orílẹ̀-èdè Kenya ti ṣetán láti fopin sí G20 Ìpèsè àdéhùn Elépo to fi léde ni oṣù kẹrin ọdún 2023.
Adehun G2G ìpèsè epo laarin Kenya àti àwọn mẹta míràn to n gbe epo jáde lagbaye láti Gulf ti ààrẹ William Ruto gbekalẹ ni ọ̀nà…
A Ṣẹ̀ Ṣẹ̀ Ń Mẹ́yẹ Bọ̀ Lápò Ni: Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles Ti Fi Àgbà Han Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Ivory…
Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Ivory Coast àti Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles figagbaga bi bọọlu ṣe bẹrẹ lori paapa ni ilaji akọkọ, ko si ẹni to mi àwọ̀n ninu orílẹ̀-èdè mejeeji yii
Ṣugbon Nigba ti wọn bẹrẹ ilaji keji, Super Eagles ni anfaani lati mi…
Mímú Ìdàgbàsókè Bá Ètò Ọ̀gbìn Se Pàtàkì Fún Àwọn Orílẹ̀-èdè Adúláwọ̀ láti Tán…
Lójúnà àti tán ìsòro ebi, kí oúnjẹ sì pọ̀ yanturu, àjọ tí ó wà fún mímú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn ti pàrọwà sí àwọn Orílẹ̀-èdè adúláwọ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọ̀gbìn
Àwọn àjọ tí ọ̀rọ̀…
Wọ́n Ti Fi Ẹ̀sùn Ìpànìyàn Kan Olórí Ẹgbẹ́ Òkùnkùn Ní Orílẹ̀-èdè Kenya Látàrí…
Adájọ́ ti pàṣẹ kí olórí ẹgbẹ́ òkùnkùn ní Orílẹ̀-èdè Kenya, Paul Mackenzie àti àwọn ọgbọ̀n míràn lọ se àyẹ̀wò ọpọlọ síwájú kí wọ́n tó kojú ẹ̀sùn ìpànìyàn níbi tí wọ́n ti sekúpa àwọn ọmọdé tí ó dín díẹ̀…
Kenya Tí Ń Ṣé Àtúnṣe Sí Ède Àìyedè Tó Wà Láàrín Rẹ̀ Àti Tanzania Lórí Òfin Ọkọ̀ Òfurufú
Njẹ́ àwọn arínrín-àjò Kenya yóò ní ànfààní látí rìn ìrìn-àjò lọ́ sí Dar Es Salam, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejilelogun, Oṣù Kínní Ọdún yìí (22-01-2024)?
Orílẹ̀-èdè Tanzania tí kéde ní ọjọ́ kẹ́ẹdógún (15th) Oṣù Kínní pé kò sí igbalaye fún…