Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ

This is a category for Africa news

Gbọ́misiomiòtó Ló Ń Ṣẹlẹ Bayii Ni Orílẹ̀-èdè Senegal Báyìí Látàrí Bí Wọ́n Ṣe Sún Ètò Ìdìbò Síwájú

Látàrí bi wọ́n ṣe sún eto Ìdìbò Síwájú ni Orílẹ̀-èdè Senegal àwọn ará ìlú n ṣe ìwọ́de èyí tó mú wọn kọlù àwọn ọlọ́pàá ni iwájú ita ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin. Ìròyìn fi to wa létí wí pé wọn kọ̀wé láti fi kún àkókò Ààrẹ to wà lórí ipo báyìí Macky…

Orílẹ̀-èdè Burkina Faso Di Orílẹ̀-èdè Áfíríkà Kejì Ti Ó Fàyè Gbà Ògùn Abẹrẹ Ajẹsara Ti Àisìán Ibà…

Láìpẹ́ yìí ni Orílẹ̀-èdè Burkina Faso di Orílẹ̀-èdè Áfíríkà Kejì tí o pàṣẹ pé kí wọn mú ògùn àisìán iba abẹrẹ ajẹsara wọ ètò abẹrẹ ajẹsara fún àwọn ọmọ wẹ́wẹ́. Orílẹ̀-èdè náà ti Kéde ògùn àisìán iba náà ti wọn pè RTS,S, sí àwọn àgbègbè…

Àjọ ECOWAS Ti Ké Sí Orílẹ̀-èdè Senegal Láti Mú Ọjọ́ Mìíràn Fún Ìdìbò Ààrẹ Tí Wọ́n…

Àjọ tó ń rísí ọrọ̀ ajé àwọn ipinlẹ Iwọ-oorun Afirika (ECOWAS) ti rọ àwọn alaṣẹ Orílẹ̀-èdè Senegal lati jára mọ mímú ọjọ tun tun fún idibo aarẹ Orílẹ̀-èdè náà tí wọn sun síwájú Agbegbe tó sọrọ yii ninu ọrọ kan ti…
button