Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ

This is a category for Africa news

Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ fún Áfíríkà yóò bẹ̀rẹ̀ ní 2028

Ààrẹ Nàìjíríà Bọla Ahmed Tinubu ti sọ pé ìjọba òun yóò jẹ́ kí ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ́ Àdúláwọ̀ ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè ẹgbẹ́ láti ri pé Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ fún Adúláwọ̀ bẹ̀rẹ̀ ní 2028, bí wọ́n ti ṣètò…

Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Pè Fún Ìwádìí Tí Ó Gbépọn Látàrí Ẹ̀sùn Ìsekúpani Tí Ó…

Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ti pè fún ìwádìí látàrí ẹ̀sùn ìpànìyàn tí ó wáyé ní àgbègbè Amhara, Ethiopia níbi tí wàhálà nla ti bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ọmọ ológun àti àwọn ará ìlu níbi tí ọgọ́rin ènìyàn ti…
button