Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Gowon Gbé Ìgbésẹ̀ Akin láti Pẹ̀tù Sí Aáwọ̀ Tí Ó Wáyé Láàrin Àjọ ECOWAS
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí, tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásilẹ̀ Àjọ ECOWAS, Ọ̀gágun Yakubu Gowon ti pàrọwà sí àjọ náà láti gbésẹ̀ lórí ìdẹ́yẹsí lórí Orílẹ̀-èdè Mali, Burkina Faso ati Niger…
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Libya Ti Pàṣẹ Kí Àwọn Alákatakítí Fi Ìlú Tripoli Sílẹ̀
Ikọ̀ alákatakítí tí ó ti ń se àkóso Ìlú Tripoli láti ọjọ́ pípẹ́ sẹ́yìn ni ó ti gbà láti fi olú ìlú Orílẹ̀-èdè Libya sílẹ̀
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé, Imad Trabelsi sàlàyé pé lẹ́yìn ìfọ̀rọ̀-wérọ̀…
Wọ́n mú àwọn òsìṣẹ́ Agbófinró Kenyan kan lórí ẹ̀sùn fàyàwọ́
Ìjọba Kenya ti gbé ìgbésẹ̀ tó ṣe pàtàkì ní bí ó ṣe ya bo ilé kan lẹ́gbẹ́ẹ Nairobi, níbi tí ọwọ́ sìnkún rẹ̀ ti ba àwọn òsìṣé Agbófinró mẹ́rin kan. Wọ́n tún rí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Ethiopia mẹ́tàdín-lógójì, tí…
Aṣáájú Àwọn Alátakò Ìjọba Tunisia Tí Wọ́n Fí Sẹ́wọ̀n Tí Bẹ̀rẹ̀ Ìkọ Oúnjẹ Sílẹ̀
Rached Ghannouchi, olórí alátakò Tunisia àtí àdarí tí ẹgbẹ́ Ennahda, tí bẹ̀rẹ̀ kíkọ oúnjẹ sílẹ̀ pẹ̀lú èròngbà látí darapọ̀ mọ́ àwọn alátakò akẹ́gbẹ́ rẹ̀.
Ìgbésẹ náà wa gẹ́gẹ́bí Irisi ìjọba láti tí àwọn alátakò rẹ̀ mọle, gẹ́gẹ́bí àwọn…
Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè DRC Ṣé Ìwọ́de Lórí Bí Rùwándà Ṣé Ń Fí Duroonu Ṣé Ìkọlù
Láìpẹ́ yìí, Orílẹ̀-èdè Democratic Republic of Congo (DRC) fí ẹsùn kàn Rwanda pé o ń ló ọkọ òfurufú duroonu láti ṣé ìkọlù sí àwọn ọkọ òfurufú ní pápá ọkọ òfurufú kàn nítòsí Goma. Àwọn ọmọ àgbègbè náà ṣé ìwọ́de ní àwọn òpópó-ònà Goma bí…
Papua New Guinea: Ìjà Ẹlẹ́yà-mẹ̀yà Sọ Ẹ̀mí Ókéré Tán Àádọ̀ta Èniyàn Nù
Ókéré tán ẹ̀mí mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ènìyàn ti segbe ninu ija ẹlẹyamẹya ni ariwa òkè orílẹ̀-èdè Papua New Guinea ni ọjọ́ ajé.
Àwọn ọkunrin náà ni wọn pa ninu ibùba ni agbègbè Enga bí ìròyìn se sọ.
Rogbodiyan náà ṣẹlẹ ni ọjọ Aiku…
Orílẹ̀-èdè Egypt: Ẹgbẹ̀rún Mẹ́wàá Asáré Darapọ̀ Láti Ṣe Àtìlẹyìn Fún Orílẹ̀-èdè Palestine
Bi ẹgbẹrun mẹ̀wá àwọn asáré ni o kópa ninu eré ìje fún Gasa ni ìlú Cairo.
Gbogbo tíkẹ́ẹ̀tì ti won tà fún eré náà ni wọn fẹ fi se atilẹyin fún àwọn ará Gaza Strip pẹlu atilẹyin kiamọ́sá.
Asare ọgbọn lati oniruru orílẹ̀-èdè lo…
Pope Pàrọwà Sí Àwọn Tí Ọ̀rọ̀ Kàn Láti Fi Òpin Sí Ogun Abẹ́lé Orílẹ̀-èdè Sudan
Pope Francis pàrọwà ní ọjọ́ Àìkú sí àwọn ikọ̀ méjéèjì tí ọ̀rọ̀ kàn láti fi òpin sí aáwọ̀ tí ó ń wáyé láti osù mẹ́wàá sẹ́yìn, níbi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti fi ibùgbé wọn sílẹ̀
Ó sàfirinlẹ̀ àrọwà…
Ètò Ìdìbò Gbogbogbòò Ti Orílẹ̀-èdè Senegal: Ẹgbẹ́ Alátakò Pè Fún Wíwáyé Ìdìbò…
Àwọn olùfẹ̀hónúhàn jáde lọ́pọ̀ yanturu ní ìlú Dakar, olú ìlú Orílẹ̀-èdè Senegal níbi tí wọ́n ti n pè fún kí ìdìbò gbogbogboo wáyé ní kíá-kíá
Ìgbésẹ̀ náà wáyé látàrí bí ilé ẹjọ́ àpapọ̀…
Orílẹ̀-èdè Egypt Se Àmójútó Ẹnu Ibodè Láti Dènà Ìkọlù Isreal
Orílẹ̀-èdè Egypt ti bẹ̀rẹ̀ láti mọ ògiri ńlá kan sí ẹnu ibodè rẹ̀ pẹ̀lú Gaza, lójúnà àti dènà ìkọlù tí ó ṣe é se kí ó wáyé sí ìlú Rafah
Látàrí wàhálà ti ó ń wáyé láàrin Isreal ati Gaza, Egypt…