Ilé Ẹjọ́ Fagilé Ìpẹ̀jọ́ Tí Ó Tako Ààrẹ Buhari
Adájọ́ Inyang Ekwo ti ilé ẹjọ́ gíga ìlú Abuja ti da ẹjọ́ tí ó tako ìyànsípò tí ààrẹ Buhari ṣe sí àjọ tí ó ń rí sí àgbègbè (Niger Delta) nu.
Onísòwò ńlá kan tí ó fi ìlú Abuja se ibùgbé, Olóyè…