Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Sàfirinlẹ̀ Àtìlẹyìn Fún Àwọn Ọlọ́pọlọ Pípé Ẹ̀dá

0 114

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó se àfirinlẹ̀ ìfarajì rẹ̀ láti se àtìlẹyìn fún àwọn ọ̀dọ́ jákè-jádò ìpínlẹ̀ fún ìdàgbàsókè ẹ̀bùn ọpọlọ wọn.

 

Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Gómìnà lórí àsà, Ọ̀gbẹ́ni Fẹmi Martins ni ó fi ọ̀rọ̀ náà léde nígbà tí ó ń fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jáde lórí iṣẹ́ ọwọ́ ní ẹ̀bùn owó.

 

Alága ikọ̀ lórí ọ̀rọ̀ àṣà ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin ní ìpínlẹ̀ náà, Fatai Oluwa, gbé oríyìn fún àwọn ọlọ́pọlọ pípé akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ náà, Ó sì gbàwọ́n níyànjú láti lo ànfààní náà bí ó ti tọ́ àti bí ó ti ṣe yẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.