Iná Ṣèyọ Nínú Ẹgàn Ní Orílẹ̀-èdè Canada
Iná inú Ẹgàn tẹ̀ síwájú láti má jó lọ ní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀ káàkiri ní Orílẹ̀-èdè Canada ti èéfín rẹ̀ sí gba gbogbo ojú ọ̀run. Eléyìí mú kí àwọn ènìyàn sá kúrò ní ilé wọn, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú nlá ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ni wọ́n sì ti ń rí…