Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Yan Àwọn Ikọ̀ Láti Se Ìwádìí Ọjà Òògùn Tó Jóná Ní Ìlú Onitsha

0 119

 

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Charles Soludo ti yan ikọ̀ ẹni mẹ́sàn án láti se ìwádìí ìṣẹ̀lẹ̀ iná tí ó wáyé ní ọjà oygùn (Ogbogwu) Onitsha, ní ọjọ́ Kejì oṣù kọkànlá, ọdún 2022.

Iná náà gba ẹ̀mí ènìyàn Mọ́kànlá, o sì ba dukia tó tó ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ̀nù jẹ́.

Igbimọ ti wọn pè ni “Fire Disaster and Kindred Matters Committee” ní wọ́n o darí láti ọwọ́ adarí tẹ́lẹ̀ Olùdíje fún ipò Gómìnà labẹ́ àsìá ẹgbẹ́ National Conscience Party, NCP, comrade Peter Okala, pẹ̀lú akọ̀wé rẹ̀ tó jẹ́ Dókítà Frank Udemadu, tó jẹ́ akọ̀wé tẹ́lẹ̀ ti ẹgbẹ́ olóògùn- Oniitsha Patient and Proprietory Medicine Dealers Association, OPPMDA.

 

Temitope Obisesan

Leave A Reply

Your email address will not be published.