Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ̀ ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dáná sun àtakò àwọn ọlọ́tẹ̀ ní Dikwa,ìpínlẹ̀…

Àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn agbófinró ti dáná sun àtakò àwọn ènìyàn kan tí wọ́n fura sí bíi jàǹdùkú,tí wọ́n kóra wọn jọ sínú mọ́tò pẹ̀lú ìbọn lọ́wọ́ lọ́tún lósì. Ni irọlẹ ojọ iṣẹgun,awọn…

COVID-19: Àwọn ènìyàn méjìlé-lọ́gọ́rùún míràn tún ti ní ààrùn covid.

Àwọn èniyàn méjìlé-lọ́gọ́rùún míràn ló tún ti ní ààrùn covid,ní báyìí, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ o din ni èjì le ni ọ́rin ènìyàn lóti ní ààrùn ọ̀hún,  ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ o le ni ọ̀kan din…

Àlùyọ tó lámì lórí ìbáraẹnisọ̀rọ̀: Pantamí Gba àmì-ẹ̀yẹ Ọdún

Mínísítà fún  ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìṣòwò ayélujára, Ísá Pantamí ti gba àmì-ẹ̀yẹ Ọdún 2020,  fún ipa rẹ̀ lórí ìgbòòrò àti ìdàgbàsókè ti ẹ̀ka Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Amin ẹyẹ ọhun, ti…

Bí a ṣe ń kọ́ṣẹ́, laṣe ń kọ́yára:Ìjọba àpapọ̀ yóò parí ọna márosẹ̀ Eko-Ìbàdàn lóṣù…

Ìjọba àpapọ̀ pinnu láti parí ọna márosẹ̀ Lagos-Ìbàdàn ní oṣù karún ọdún 2022 Ni ọjọ iṣẹgun,ile igbimọ aṣoju ti fun awọn alagbaṣe ti o n ṣakoso iṣẹ atunla ọna marosẹ Lagos-Ibadan ni oṣu karun un,ọdun 2022,lati pari ọna mejeeji…

Ojúmọ́ tuntun àrà tuntun:Wọ́n tún jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé ní ìpínlẹ̀ Niger

Àwọn ọlọ́pàá ti fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé lótìtọ́ọ́ ni àwọn kan ti fipá kó àwọn ọmọ ilé-kéu ́ọkùnrin kan  kúrò ní ilé-ìkawé wọn ní agbègbè Tegina ní ìjọba ìbílẹ̀ Rafi, ipinlẹ Niger ní ọjọ́ àìkú. Gẹgẹ bii agbẹnusọ…
button