Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ̀ ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dáná sun àtakò àwọn ọlọ́tẹ̀ ní Dikwa,ìpínlẹ̀ Borno.

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

66

Àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn agbófinró ti dáná sun àtakò àwọn ènìyàn kan tí wọ́n fura sí bíi jàǹdùkú,tí wọ́n kóra wọn jọ sínú mọ́tò pẹ̀lú ìbọn lọ́wọ́ lọ́tún lósì.
Ni irọlẹ ojọ iṣẹgun,awọn onijagidijagan ọhun kabamọ lọwọ awọn ọmọ ogun ti owa ni igboro Dikwa.
PRNigeria gbọ pe, ọpọlọpọ awọn onijagidijagan ti wọn fura si pe wọn jẹ awọn ọmọ ogun ISWAP ti o ṣẹṣẹ ṣẹgun awọn Boko Haram ti Shekau, kọlu igboro Borno logunlọgọ pẹlu ibọn lowọ.
ki wọn to le koju awọn aladugbo ti laasigbo ti da riboribo tẹlẹ,gẹgẹ bi alaabo kan ṣe ṣalaye, bayi ni awọn ikọ omọ ogun ati agbofinro koju wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.