Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àwọn ènìyàn méjìlé-lọ́gọ́rùún míràn tún ti ní ààrùn covid.

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

97

Àwọn èniyàn méjìlé-lọ́gọ́rùún míràn ló tún ti ní ààrùn covid,ní báyìí,

ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ o din ni èjì le ni ọ́rin ènìyàn lóti ní ààrùn ọ̀hún,  ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ o le ni ọ̀kan din ni ọ́ta-le-nigba sì ti gba ìwòsàn, tí ẹ̀ta din ni okòó-le-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá sì ti jẹ́pè ọlọ́run.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.