Take a fresh look at your lifestyle.

Àlùyọ tó lámì lórí ìbáraẹnisọ̀rọ̀: Pantamí Gba àmì-ẹ̀yẹ Ọdún

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

103

Mínísítà fún  ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìṣòwò ayélujára, Ísá Pantamí ti gba àmì-ẹ̀yẹ Ọdún 2020,  fún ipa rẹ̀ lórí ìgbòòrò àti ìdàgbàsókè ti ẹ̀ka Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Amin ẹyẹ ọhun, ti iwe iroyin Blueprint ṣe agbatẹru  rẹ, ti o tun jẹ ayẹyẹ ati  ajọdun ọdun kẹwa  2020 impact Series/award ni Abuja

O jawe olubori nipasẹ aṣeyọri pataki ni agbegbe pataki mẹta-iṣowo,ifihan gbangba ati aabo,ati ọna ara  ti o gba  ṣe iṣẹ didari ẹka ibaraẹnisọrọ ti eyelujara.

Aarẹ ile igbimọ awọn ọmọ aṣofin ati awọn ọmọ aṣofin pataki miran ni awujọ  lowa nibi ayẹyẹ ami-ẹyẹ ọhun.    ọpọlọpọ awọn olugbami ẹyẹ bii, aarẹ orilẹ-ede nigbakan ri ati awọn gomina ni wọn gbami ẹyẹ ni ọpọlọpọ ipele fun awọn aṣeyọri lori igbiyanju  loriṣiriṣi lori adawọle wọn.

Minisita naa, ti Oluranlọwọ imọ-ẹrọ ṣe aṣoju  rẹ, Dokita Femi Adeluyi dupẹ lọwọ awọn oluṣeto ọhun fun riri awọn aṣeyọri  wọn ni ẹka Ibaraẹnisọrọ ati iṣowo.

Leave A Reply

Your email address will not be published.