Take a fresh look at your lifestyle.

Ojúmọ́ tuntun àrà tuntun:Wọ́n tún jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé ní ìpínlẹ̀ Niger

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

109

Àwọn ọlọ́pàá ti fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé lótìtọ́ọ́ ni àwọn kan ti fipá kó àwọn ọmọ ilé-kéu ́ọkùnrin kan  kúrò ní ilé-ìkawé wọn ní agbègbè Tegina ní ìjọba ìbílẹ̀ Rafi, ipinlẹ Niger ní ọjọ́ àìkú.

Gẹgẹ bii agbẹnusọ fun ile-isẹ awọn ọlọpaa ipinlẹ-Niger, Wasiu Abiọdun,awọn adigunjale ọhun ṣigun wa si igboro Tegina lori ọkada ti wọn si n yinbọn lọtun-losi, ti wọn si fipa ko awọn ọmọde ti  iye won to igba (200), ti wọn n kọ ẹkọ keu ni ile-ẹkọ isilamu ti Salihu Tanko,ni Tegina.

O  wa sọ pe,ikọ awọn ọlọpaa ọhun ti fọn awọn ọlọpaa ati operation puff 2  si agbegbe naa lẹsẹkẹsẹ lati ran awọn to farapa lọwọ, ti won yoo ṣi gba awọn ọmọ naa gba pada lọwọ awon ajinigbe.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.