Take a fresh look at your lifestyle.

Ewu: Pàtàkì ipa obìnrin láti mú àláfíà jọba láyíká wọn

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

96

Àjọ tó ńrísí ìbáṣepọ̀ gbogbo àgbáyé UN ti sọ pé ,óṣe pàtàkì púpọ̀ láti gba àwọn obìnrin láyè lórí ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ìfọ̀rọ̀wérọ̀.

Ajo Agbaye (UN), ti pe fun ifisi ni kikun ati ikopa awọn obirin ninu ijiroro ati eto ifọrọwerọ ni oriṣiriṣi ipele lati ṣe ijiroro lori awọn ọna lati koju awọn alafo,idena ati lati janfaani agbara ilaja to gbooro ti awọn obinrin Naijiria ni lati koju ewu.
Nigbati o n sọrọ, Aṣoju Awọn Obirin UN si orilẹ-ede Naijiria ati ajọ to nrisi aṣepọ okowo awọn adulawọ ECOWAS, Comfort Lamptey, sọ pe iṣiro fun imuṣẹ awọn ilana maa nle waye ti awọn obinrin bajẹ olupẹtu.
O ṣe afikun pe ikopa Awọn Obirin maa mu ki alaafia jọba lagbegbe wọn ,pẹlu agbara wọn ,ibaṣepọ wọn si fakọyọ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.