Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19 :Ọgbọ̀n ènìyàn mírán tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

46

Àwọn ènìyàn ọgbọ̀n míràn tún ti fara káàsá ààrùn covid,lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí,àwọn ènìyàn ẹgbàáta le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ o le ni àrún din ni okòó lelọ́ọ̀dúnrún lótún ti ní ààrùn ọ̀hún.

Gẹgẹ bii tweet naa ṣe lọ,Lagos state:mẹrindin-lọgbọn,Rivers:mẹta,Kwara:ẹyọkan pere.

Bakannaa,ile-iṣẹ apapọ to nmojuto ajakalẹ aarun ni orilẹ-ede sọ ninu tweet ọhun pee ,ni ọgbọnjọ oṣu karun,awọn to ti ni aarun naa ti jẹ ẹgbaata le ni ọkẹ mẹjọ ole ni arun din ni okoo lelọọdunrun,ti awọn to ti gba iwosan si jẹẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abo din ni èjì-le-ni-ojì le ni irinwó,ti ọ̀kan-din-ni-ojì din ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá si ti jẹ ọlọrun nipe.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.