Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí ‘A gbọ́dọ̀ rẹ́yìn ààrun kògbóógùn èèdì títíi 2030‘

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

110

Ààre Mùhámmádù Bùhárí ti pè fún ìgbésè tuntun jákèjádò orílẹ̀-èdè  àgbáyé, nípa ṣíṣàtúnṣe lóríi àjàkálẹ̀ ààrùn kògbóógùn éédì [HIV/AIDS] ní agbègbè adúláwọ̀ àti rírẹ́yìn ààrùn ọ̀hún t́itíi ọdún 2030.

Aarẹ ṣalaye eyi ninu fidio kan ti o fi ranṣẹ si ipade ipele gbogbogboo ti ajọ agbaye [UNGA] lori aarun kogboogun eedi.

Ipade na ṣe atunyẹwo ilọsiwaju lori ifọkansi  atirẹyin aarun kogboogun naa ko to di ọdun  2030, ati lati pese igbaniniyanju  ti yio je gẹgẹ bii  itọsọna ati atẹle idahun ni awọn orilẹ-ede.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.