Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fikún ẹ̀bùn owó àwọn olùdíje tí wọ́n gbàmì ẹ̀yẹ òlìmpíkì…

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fikún ẹ̀bun owó  àwọn olùdíje Nàìjíríà, ní Òlíńpíkì,Tokyo 2020, ti ń lọ lọ́wọ́ báyìí ní ìlọ́po mẹ́ta. Oludari, apapọ ati Ẹka Awọn elere idaraya, FEAD ti Ile -iṣẹ Idagbasoke Awọn…

Àjọ ẹgbẹ́ aṣàgbéyẹ̀wò ọmọ Yorùbá rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àjọ àgbáyé UN lórí ààbò…

Ẹgbẹ́ kan, àjọ aṣàgbéyẹ̀wò ọmọ Yorùbá, YAF ti kọ ìwé ẹ̀bẹ̀ sí àjọ àgbáyé UN, EU àjọ aláwọ̀ funfun àti àjọ adúláwọ̀ AU,láti ran àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò  orílè-èdè Nàìjíríà lọ́wó lórí àwọn tí wọ́n ń gbèrò…

Igbákejì ààrẹ, Òsínbàjò ń darí ìgbìmọ̀ ìjọba àpapọ̀

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè,ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò ń darí  ìgbìmọ̀ ijọba apapọ aláṣẹ lórí ayélujára,èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ ní agogo mẹ́wàá òwúrọ̀ ní ọjọ́ọ́rú. O jẹ ipade igbimọ  akọkọ lati igba ti aarẹ Muhammadu…

Ìkọlù Àwọn ọlọ̀tẹ̀: Nàìjíríà, UK Ṣèlérí Ìdájọ́ òdodo Fún Gbogbogbòò

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí àti ọ̀gá àgbà Mínísítà Boris Johnson, ti Ìlú Gẹ̀ẹ́sì ní ọjọ́bọ̀, ṣe àtúnyẹ̀wò ìgbógunti  àwọn oríṣiríṣi ìwà jàgídíjàgan ní Nàìjíríà, àti pé ó tún gbà pé  wọ́n ní láti…

Ìṣòwò orí ayélujára: Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò jàǹfààní ìpàtẹ ìbáraẹnisọ̀rọ̀…

Ìjọba Nàìjíríà yóò jàǹfààní níbi ìkópa rẹ̀ níbi  Àfihàn Ìmọ̀-ẹ̀rọ  ìbáraẹnisọ̀rọ̀ lórí omi òkun (GITEX) 2021 láti túnbọ̀ ṣàwárí àjọṣepọ̀ káríayé fún ìyípadà orílẹ̀-èdè lórí ọrọ̀ ajé orí…
button