Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Ènìyàn mọ̀kàn-dín-ní-òjì̀ dín ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

62

Ènìyàn mọ́kàn-dín-lójì-dín-ní-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta míràn tún ti ní ààrùn covid,tí ènìyàn méjì sì ti jẹ́pè olúwa.

Ile-iṣẹ to n mojuto ajakalẹ aarun ,NCDC fidiẹ mule ni ọjọ abamẹta, ni oju opo wẹẹbu rẹ.

Awọn eniyan mokan-din-loji-din-ni-ẹedẹgbẹta ọhun jẹyọ ni awọn ipinlẹ mẹtala wọnyii-

Lagos (igba-le-mọkan-din-logun), Akwa Ibom (mejile-lọgọrun),Ondo (meta-din-logoji) ,Oyo(mẹtale-lọgbọn) ,Kwara (mọkan-din-logun), Rivers (mẹrin-din-logun) ,Ekiti (mẹẹdogun) ,Delta (mẹrinla),Ogun (meje),FCT(marun), Niger (meji) ,Edo (Ẹyọkan),Katsina (Ẹyọkan) gẹgẹ bii ile-iṣẹ ọhun ṣe sọ.

Ni  bayii,eniyan ẹ̀ẹ́dẹ́gbàsán- o- le- ni ẹ̀rin- din- làádọ́rùn lo ti ni aarun naa, ẹgbàáta- le- ni- ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ- o- din- ni ẹ̀ta- din-  loojì ti gba iwosan, ti eétalá din ni ẹgbẹ́ọ̀kànlá si ti jẹpe oluwa.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.