Take a fresh look at your lifestyle.

NSIP: Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣàtúnṣe GEEP, tí ó sì tún ṣe ìfilọ́lẹ̀ GEEP 2.0

Ìjọba orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà ti ṣe ìfilọ́lẹ̀  ètò ìṣèránlọ́wọ́ alábọ́dé GEEP 2.0, GEEP 2.0,èyí tí wọ́n ṣàgbékalẹ̀ rẹ̀ láti yá àwọn ènìyàn lówó àti láti kọ́ àwọn ará ìlú tí kò níṣẹ́  ọwọ́ níṣẹ́ lọ́lọ́kan…

Ààrẹ Bùhárí ṣèdárò oloogbe ìyá-ààfin Victoria Aguyi-Ironsi ìyàwó ààrẹ àkọ́kọ́ fún…

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti bá ìdílé Aguiyi-Ironsi, ìjọba àti àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Ábiá kẹ́dùn lórí ikú Olóyè Ìyáàfin Victoria Aguiyi-Ironsi,ẹni tí ó jẹ́  ìyàwó Olórí ìjọba àpapọ̀ àkọ́kọ́, ajagun…

Ìmọ̀ ayélujára le ṣàlékún Ìdàgbàsókè ìbáṣepọ̀ ọrọ̀ -ajé-NCC

Igbákejì  Aláṣẹ alága àti  Aláṣẹ àgbà  Ìgbìmọ̀ ilé-iṣẹ́ tó ń rísí Ìbáraẹnìsọ̀rọ̀  ní orílẹ̀-èdè Nàìjíŕià (NCC), Ọ̀jọ̀gbọ́n Umar Danbatta, sọ pé,ìmọ̀ ayélujára yóò ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ará ìlú láti…

Orílè -èdè Nàìjíríà ṣe ìrántí àyájọ́ ọjọ́ òwò ẹrú jákèjádò Àgbáyé àti…

Lónìí, Nàìjíríà yóò darapọ̀ mọ́ gbogbo àgbáyé láti ṣe ìrántí àyájọ́ ọjọ́ òwò ẹrú ọlọ́dọọdún àti ìparun rẹ̀. Akori ti ayẹyẹ ọdun yii ni “ẹru ode-oni, Ibeere lapapọ: Idaabobo Ọjọ Ọla” Ayẹyẹ naa, eyiti wọn ṣeto…

Nàìjíríà yóò ya Ọjọ́ kan sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ọjọ́ àyájọ́ Fún Àwọn Àgbàlagbà Láìpẹ́…

Mínísítà fún ètò ọmọnìyàn, gbígbógun ti Àjálù àti Ìdàgbàsókè Àwùjọ, Hájìyá Sàdíyá Umar Farouq, ti fidánilójú pé, wọ́n yóò kéde yíya ọjọ́ kan pátákí sọ́tọ̀ fún àwọn àgbàlagbà láìpẹ́. Farouq mu…
button