gbígbógun ti òògùn olóró: Nàìjíríà, Saudi Arabia ṣerawọn lóṣùṣù ọwọ̀
Eyitayọ Fauziay Oyetunji
Ilé -iṣẹ́ tó ń ṣòfin lórí òògùn olóró ní Orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà, NDLEA àti Olùdarí ẹka to n gbogun ti oogun oloro lorilẹ ede Saudi Arabia (GDNC), ti gbà láti tùbọ̀ fìdí àjọṣepọ̀ wọn múlẹ̀ lórí gbígbógun ti gbígbé àti mimu òògùn olóró láàrin àwọn orílẹ̀ -èdè méjèèjì.
Eyi ni koko ijiroro ti NDLEA, ajagunfẹyinti Mohammed Buba Marwa ati aṣoju Saudi GDNC, Naser Hajid Al Otaibi, jọ se niluu Abuja,lorilẹ ede Naijiria.
Lakooko to n itẹwọgba awọn aṣoju Saudi, ajagunfẹyinti Marwa fi imoore rẹ han fun atilẹyin lati ọdọ ijọba Saudi latẹyinwa.
Oludari NDLEA bẹbẹ fun iranlọwọ lati ọdọ ijọba orilẹ ede Saudi fun atilẹyin wọn .
Leave a Reply