Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀ èdè Nàíjíríà àti Bulgaria yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ lórí ètò ààbò

90

Minisita fun eto aabo lorilẹ ede Naijiria , ọgagun ajagunfẹyinti  Bashir Salihi Magashi  ti ni orilẹ ede Naijiria  ati orilẹ ede  Bulgaria  yoo fọwọsowọpọ lori eto aabo.

Minisita fun eto aabo sọrọ naa lasiko ti o gba asoju orilẹ ede Bulgaria,Yanko V. Yordanov, lalejo niluu Abuja .

Asoju orilẹ ede Bulgaria,Yanko V. Yorda naa wa lo anfaani ọhun lati fi pe minisita fun eto aabo lorilẹ ede Naijiria gẹgẹ  bi alejo pataki si ipatẹ ọjà ológun ti wọn yoo se ni orilẹ ede  Bulgaria ni Oṣu Kẹfa ọdun to n bọ.

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.