Ààrẹ Bùhárí yọ mínísítà ètò ọ̀gbìn àti mínísítà fún iná mọ̀nà –mọ́ná ńipò
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí kéde àtúntò ráńpẹ́ nínú àwọn mínísítà rẹ̀, tí èyí sì bá mínísítà mẹ́rin.
Meji ninu awọn mẹrẹẹrin naa ni lati fi ipo silẹ ti meji si lọ di ipo miran mu.
Awọn to yọ nipo ni…