Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin fọwọ́ sí owó ìṣètò ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ìmọ̀-iṣé Ìlera àti ti ìmọ̀…

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fi òǹtẹ̀ lu  àwọn òfin méjì láti dá ilé ẹ̀kọ́ gíga fáfitì àpapọ̀ ìmọ̀ ìlera sáyẹ́ńsì, sílẹ̀ ní Otukpo  ní Ìpínlè Benue àti ti ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀…

Ààrẹ orílè-èdè Nàìjíríà kí Orílè-èdè Ṣáínà fún àjọ̀dún ọgọ́rún ọdún ẹgbẹ́…

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mùhámmádù Bùhárí ti ránṣẹ́ ìkíni  sí ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ ti orílẹ̀-èdè Ṣáínà, ààrẹ Xi Jinping lórí ayẹyẹ àjọyọ̀  ọgọ́rùún ọdún  tí wọ́n dá ẹgbẹ́ kọ̀múnísítì ti Ṣáínà sílẹ̀.…

Mítà iná mọ̀nàmọ́ná mílíọ́nù mẹ́fà lóti wà nílẹ̀ fún àwọn ará ìlú báyìí

Olùdárí Alákóso, Ilé-iṣẹ́ tó ń  ṣàkóso iná mọ̀nàmọ́ná ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NEMSA àti ọ̀ga àgbà Olùyẹ̀wò iná mọ̀nàmọ́ná lápapọ̀, Peter Ewesor sọ pé, Ìjọba  ti gbèrò láti gbé  àwọn mítà iná…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní máa gbà lára èrè lori àwọn amáyédẹrùn…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣetán láti lo òfin tó fún ìjọba lágbára láti gba owó -orí lára èrè  orí àwọn amáyédẹrùn àgbáyé àti àwọn ilé-iṣẹ́ ayélujára tó ṣe pàtàkì sí ọrọ̀ ajée Nàìjíríà. Alaye kan…

Dí́dá Iṣẹ́ sílẹ̀:Ọ̀gá ajagunfẹ̀yìntì gba ìjọba níyànjú ìfọwọ́sowọ́pọ̀

Ajagunfẹ̀yìntì ọ̀hún rọ ìjọba láti fàyè gba Àwọn ilé-iṣẹ́ Kékeré àti Alábọ́dé (SMEs) láti dá iṣẹ́ sílẹ̀. Ọga agba ajagunfẹyinti,Azubuike Ihejirika,pe ipe yii nibi ifilọlẹ aṣẹ ajọ iṣowo Ó  rọ Ìjoba Nàìjíríà láti…

Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti ṣetán fún ìyẹ̀wò àtúńyẹ̀wò ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ kejì -Ilé iṣẹ́…

Ìjoba Nàìjíríà sọ pé òhun ti ṣetán fún àjọ tó ń rí sí ìdàgbàsókè ìlú adúláwọ̀ láti sàtúńyẹ̀wò ẹlẹ́gbẹ́ kejì orílẹ̀-èdè  ara ẹni. Agbẹnusọ fun aarẹ, Femi Adesina ṣe afihan eyi ni ọjọọru, lakoko ti o n…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò túnbọ̀ tẹra mọ́ ìdókòwò wọn pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Bẹ́ljíọ́mù

Aṣojú orílẹ̀-èdè  Nàìjíríà sí Bẹ́ljíọ́mù, Obinna Onowu, ti ṣèlérí láti jẹ́ kí àjọṣepọ̀  ọrọ̀-ajé jinlẹ̀ láàrin Nàìjíríà àti Bẹ́ljíọ́mù jákèjádò gbogbo àwọn ẹ̀ka. Ọgbẹni Onowu sọ eyi lakoko ti o n fi awọn…

Ilé-iṣẹ́ tí ó ń risí ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ NCC bẹ̀rẹ̀ àtúnyẹ̀wò ìlànà láti gba…

Ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó ètò  ìbáraẹnisọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, (NCC) ti bẹ̀rẹ̀ ìlànà fún àtúnyẹ̀wò gbígbà ìwé-àṣẹ láti dá irú ilé-iṣẹ́ ọ̀hún sílẹ̀, tí ó wà tẹ́lẹ̀ fún ilé-iṣẹ́ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ti…
button