Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin fọwọ́ sí owó ìṣètò ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ìmọ̀-iṣé Ìlera àti ti ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ amáyédẹrùn

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 253

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fi òǹtẹ̀ lu  àwọn òfin méjì láti dá ilé ẹ̀kọ́ gíga fáfitì àpapọ̀ ìmọ̀ ìlera sáyẹ́ńsì, sílẹ̀ ní Otukpo  ní Ìpínlè Benue àti ti ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ amáyédẹrùn, ní Suleja ní Ìpínlẹ̀ Niger.

Igbayọhunda  awọn owo mejeeji tẹle imọran awọn iroyin   ọtọọtọ meji tatọdọ awọn Igbimọ lori Ilera (ile-ẹkọ giga ati ile ẹkọ fafiti); ati ti Awọn ile-ẹkọ giga ati TETFUND.

Alaga  Igbimọ lori Ilera, ọmọ ile igbimọ aṣofin Yahaya Oloriegbe sọ pe, igbayọhunda  iwe-owo  lati da ile-ẹkọ giga fafiti imọ sayẹnsi,Otukpo silẹ, yoo ṣe ofin atilẹyin fun ile ẹkọ eyiti o ti wa tẹlẹ.

Aṣofin naa ṣalaye pe iwe-owo ọhun , yatọ si awọn nkan  miiran;yoo koju abawọn ni gbigba awọn akẹkọ  ti o fẹ  kẹkọọ imọ Oogun ati Awọn imọ-ẹkọ ti o so mọ ni Naijiria.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button