Ìjọba Nàíjíríà gbé Àwọn òfin tí yóò dáàbò bomi kalẹ̀
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé òhun ti pinnu láti pésé àwọn ètò ìmúlò tí yóò dáàbòbò, ṣàkóso àti ṣe ìlànà gbogbo àwọn orísun omi ní orílẹ̀ -èdè fún àǹfàní gbogbo ènìyàn.
Minisita fun Awọn orisun Omi,…