Làásìgbò ìpínlẹ̀ Plateau: Ilé-iṣẹ́ ààrẹ pè fún Ìfọ̀kànbalẹ̀
Ààrẹ ti pe gbogbo àwọn agbègbè tí làásìgbò ti ń ṣẹlẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Plateau láti fiyè dénú, kí wọn sì gba àlááfìà láyè ní Ìpínlẹ̀ náà.
Oluranlọwọ pataki fun Aarẹ lori ọrọ iroyin ati Ikede, Garba Shehu pe…