Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ

This is a category for politics news

PDP pe àwọn aṣòfin tó fi ẹgbẹ́ sílẹ̀ lọ sí òmíràn ní Rivers láti fi ipò sílẹ̀

Ẹgbẹ́ alátakò Nàìjíríà, the Peoples Democratic Party, PDP, ti dúró lórí pé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ ìpínlẹ̀ Rivers mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n tó ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ All Progressives Congress, APC gbọ́dọ̀ fi ipò wọn sílẹ̀. Ẹni…

Awuye-wuye Ìpínlẹ̀ Rivers Ń Tẹ̀síwájú Èyí Tí Ó Mú Kí Àwọn Kọmísọ́nà Kọ̀wé Fipò…

Kọmísọ́nà Fún Ètò Ẹ̀kọ́ ní Ìpínlẹ̀ Rivers, Ọ̀jọ̀gbọ́n Prince Mmom ti darapọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ méjì tí wọ́n kọ̀wé fipò sílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Rivers   Mmom síṣọ lójú ọ̀rọ̀ náà pẹ̀lú ìwé tí ó kọ ráńsẹ́ sí…

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Pàrọwà Sí Àjọ Ọlọ́pàá Láti Mú Ìdàgbàsókè Bá Ètò Àbò

Ìgbìmọ̀ Ilé Asòfin lóri ọ̀rọ̀ Ọlọ́pàá ti rọ Mínísítà Fún Ọ̀rọ̀ Ọlọ́pàá àti ọ̀gá àgbà àpapọ̀ Àjọ Ọlọ́pàá láti gbé ìgbésẹ̀ tí ó yẹ láti ríi dájú pé ètò àbò tí ó péye wà jákè-jádò Orílẹ̀-èdè…
button