Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Ṣẹ́nitọ̀ Láti Ìpínlẹ̀ Anambra Pin Àwọn Ohun Elo Irinṣẹ́ Tó Lé Ní Ẹgbẹrun Méjìlá.
Aṣojú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tó n sójú ìpínlẹ̀ Anambra, Ṣẹ́nitọ̀ Tony Nwoye ti ṣe ojúṣe rẹ nípa ṣíṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà
Àwọn ohun èlò irinṣẹ́ to tó ẹgbẹ̀rún Méjìlá, ni àwọn ènìyàn jẹ ànfààní rẹ.
Àwọn tó jẹ Ànfààní…
Sẹ́nétọ̀ Ewuga Àti Àwọn Ènìyàn Pàtàkì Míràn Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Ní Ìpínlẹ̀…
Alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú APC Alhaji Abdullahi Ganduje ti tẹ́wọ́gba mínísítà kejì tẹ́lẹ̀rí fún olú ìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sẹ́nètọ̀ Solomon Ewuga àti àwọn ènìyàn pàtàkì míràn sí inú ẹgbẹ́ òsèlú APC…
Ìdìbò Gómìnà Kogi: APC rọ INEC láti fòpin sí àbojúwò àwọn èròjà ìdìbò
Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC ti rọ Ìgbìmọ̀ olómìnira tí ń mójútó ètò ìdìbò lórílẹ̀-èdè, INEC láti dáwọ́ àbojúwò àwọn èròjà ìdìbò gómìnà ti wọn lò ní Ọjọ́bọ̀, ọjọ́ kọkànlá, oṣù…
PDP pè fún ìṣèjọba tó dára, àtúnṣe lóri ètò ààbò ní Nasarawa
Ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party, PDP ti ikọ̀ ìpínlẹ̀ Nasarawa ti rọ Gómìnà Abdullahi Sule láti ṣàtúnṣe lórí ààbò àwọn ọmọ ìlú àti àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ náà.
O ṣe irawọ ẹbẹ yii nitori bi iwa aburu ajinigbe,…
Sẹ́nétọ̀ Pàrọwà Sí Ìjọba Àpapọ̀ Láti Ńi Ìfaradà Pẹ̀lú Ìgbésẹ̀ Ìjọba Àpapọ̀
Sẹ́nétọ̀ Orji Uzor Kalu ti pàrọwà sí ọmọ Nàìjíríà láti fún ìjọba àpapọ̀ ní àsìkò díẹ̀ si lójúnà àti wá ojútùú sí àwọn ìsòro tí ó ń kojú Orílẹ̀-èdè
Ó sọ ọ̀rọ̀ náà ní ọjọ́ Ìṣégun nígbà…
Adari Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Anambra Ki Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kú Ayẹyẹ ọdún Tuntun
Adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Anambra, Somtochukwu Udeze tí fí da àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lójú pàápàá jùlọ àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Anambra wí pé nínú ọdún tuntun yìí , wọn yóò gbádùn òfin àti ìdájọ tí kò ní àbùkù.
Nínú ọ̀rọ̀ ìkíni…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa Kẹ́dùn Pẹ̀lú Maidoya Lórí Ikú Aya
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa, Abdullahi Sule ti kẹ́dùn pẹ̀lú olùdíje sí ipò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú NNPP, Alhaji Abdullahi Yakubu, èyí tí ó wáyé ní ọjọ́ kejìdínlógún osù kẹta lórí ikú aya rẹ̀, Hajiya Sa’ida…
Àwọn Gómìnà Gúsù Iwọ̀ Oòrùn Se Àbẹ̀wò Sí Ibadan Fún Ìkẹ́dùn Ìpapòdà Akeredolu
Mẹ́ta nínu ́àwọn gómìnà Gúsù Iwọ̀ Oòrùn ti gúnlẹ̀ sí ọ́ọ́fìsì ìjọba ní ìpínlẹ̀ Ọyọ, Agodi, Ibadan
Lára wọn ní Dapọ Abiọdun (Ogun), Ademola Adeleke (Ọsun), ati Abiọdun Oyebanji (Ekiti) níbi tí igbákejì…
Gómìnà Tuntun Fún Ìpínlẹ Ondo Se Àbẹ̀wò Sí Ìdílé Akeredolu
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ondo Tuntun tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ búra fún, Lucy Aiyedatiwa ti se àbẹ̀wò ìbáni kẹ́dùn sí ìdílé gómìnà ìpínlẹ̀ náà tẹ́lẹ̀rí, Arakunrin Rotimi Akeredolu ní ìlú Ibadan níbi tí o ti fi àrídájú hàn pé…
Làásìgbò òṣèlú Rivers: Wike gbóríyìn fún bí ààrẹ ṣe la ìjà náà
Mínísítà fún olú ìlú (FCT), Ọ̀gbẹ́ni Nyesom Wike, ti sọ pé ó yẹ kí á yin ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu fún bí ó ṣe la ìjà làásìgbò òṣèlú ní ìpínlẹ̀ Rivers, Gúsù Nàìjíríà.
Minisita sọ eleyi lasiko ayẹyẹ ogun…