Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ

This is a category for politics news

Gbajabiamila gbóríyìn fún ètò ìdìbò, pè fún ìrànlọ́wọ́ láti fòpin sí adigunjalè

Ọ̀gá àgbà fuń àwọn òṣìṣẹ́ ààrẹ Tinubu, Ọ̀gbẹ́ni Fẹmi Gbajabiamila ti gbóríyìn fún ìgbìmọ̀ olómìnira tí ń mójútó ètò ìdìbò lórílẹ̀-èdè, INEC fún bí ó ṣe ṣètò àdìkù ìbò nírọ̀wọ́ rọsẹ̀ ní Surulere…

Àwọn òsìṣé elétò ààbò, òṣìṣẹ́ INEC gúnlẹ̀ lásìkò fún ìbò àdìkù ní ìpínlẹ̀…

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òsìṣé elétò ààbò ni ó ti gúnlẹ̀ sí Ikare-Akoko àti àyíká ìlú náà fún àdíkù ìbò fún ipò ilé ìgbìmọ̀ aṣojú fún Àríwá-Gúsù Akoko àti Àríwá-iwọ̀ oòrùn Akoko, ti agbègbè ìjọba…
button