Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI

This is a category for LATEST NEWS

Mínísítà fún Ètò Ẹ̀kọ́ pè fún Ẹ̀kọ́ Ìmọ̀ Iṣẹ́ ọwọ́ nínú Àtúnṣe NYSC

Mínísítà fún Ètò Ẹ̀kọ́, Ọ̀gbẹ́ni Maruf Olatunji Alausa, ti ṣàpéjúwe àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà bíi ohun tó níyì jùlọ láti wa ọkọ́ ìdàgbàsókè ẹ̀kọ́, ètò ìlera, àti ìdàgbàsókè ọrọ̀ ajé. O sọ eleyi lasiko ti o…

Ìyàwó Gómìnà Èkó pè fún Àlàáfíà, Ìṣètọrẹ ànúú bí oṣù Ààwẹ̀ ṣe parí

Ìyàwó Gómìnà Èkó, Dokita Claudiana Ibijoke Sanwo-Olu ti rọ àwọn ará ìlú láti jẹ́kí ẹ̀mí  Àlàáfíà, Ìṣètọrẹ ànúú, àti Ìṣọ̀kan máa báwọn gbé, bí oṣù Ààwẹ̀ ṣe parí. Nigba ti o n ba awọn Musulumi sọrọ ni…
button