Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI

This is a category for LATEST NEWS

Àjíǹde: Adarí ilé, Igbákejì rọ àwọn kírísítíẹ́nì láti kọ́ ìṣe kŕisítì

Adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú, ọ̀gbẹ́ni Abbas Tajudeen àti igbákejì rẹ̀ Benjamin Kalu ti rọ àwọn ọmọ lẹ́yìn kírísítí láti kọ́ ìṣe ìfaradà Jésù Kírísítì. Wọn rọ awọn ọmọ Naijiria lati ni ifẹ ara wọn lai bikita ẹya, ẹsin,…

Ilé iṣẹ́ tí ń mójútó Ìrìn àjo lọsí orílẹ̀-èdè mìíràn dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè…

Ilé iṣẹ́ tí ń mójútó Ìrìn àjo lọsí orílẹ̀-èdè mìíràn ní Nàìjíríà (NIS), Aala Agbofinro Illela ti ipinlẹ Sokoto, ti fidiẹ mulẹ pe wọn ti dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Mali méjìlé-lọ́gọ́ta padà lati oju ile Illela.…

Hajj 2025: Eko Ṣonígbọ̀wọ́ àyẹ̀wò ìlera fún àwọn tó fẹ́ rìnrìn àjò mímọ́

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Eko, Ọ̀gbẹ́ni Babajide Olusola Sanwo-Olu àti igbákejì rẹ̀, Dókítà Kadri Hamzat ti Ṣonígbọ̀wọ́ àyẹ̀wò ìlera pataki fún àwọn tó fẹ́ rìnrìn àjò mímọ́ lọ sí orílẹ̀ èdè Saudi Arabia láti ìpínlẹ̀ Eko.…

Àjíǹde: Gómìnà pè fún ìgbàmọ́ra, Ìrẹ́pọ̀ kí Nàìjíríà lè dára jùlọ

Gómìnà Ìpínlẹ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Soludo, kí àwọn ọmọ lẹ́yìn Krísítì kú ọdún Àjíǹde, tí ó sí pè fún ìgbàmọ́ra, Ìrẹ́pọ̀ kí Nàìjíríà lè dára jùlọ. Ninu afiranṣẹ kan lati ọdọ akọwe awọn Akọroyin…

Agb́abọ́ọ́lù ọmọ orílẹ̀-èdè Gabon, Aaron Boupendza di olóògbé nínú ìṣẹ̀lẹ̀ aburú kan

Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ́lù Gabon (FEGAFOOT), ti fìdí ikú ọmọ agbábọ́ọ́lù fún orílẹ̀-èdè,  Aaron Boupendza múlẹ̀ nínú àlàyé kan tí ó fi síta ní Ọjọ́ọ́rú. Gẹgẹ bi alaye naa ṣe sọ, agbabọọlu ti o jẹ ọmọ ọdun mejidin-lọgbọn, ti…

Ààrẹ Tinubu Ṣàfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ ìpele gíga fún ètò ìkànìyàn orílẹ̀-èdè

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti Ṣàfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ ìpele gíga láti bẹ̀rẹ̀ ètò ìkànìyàn àti ìṣèṣirò àwọn ọmọ Nàìjíríà àti ilégbèé wọn. Igbimọ naa yoo ṣafihan ijabọ adele laarin ọse mẹta, leyin naa ni yoo wa ṣeto…

Agbófinró ìpínlẹ̀ Adamawa, Àwọn Akọ̀ròyìn fọwọ́sowọ́pọ̀ láti túnbọ̀ gbé ètò ààbò ró

Lára ìgbésẹ̀ láti ṣe ìgbélárugẹ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin Agbófinró àti Akọ̀ròyìn, Kọmíṣọ́nà fún Agbófinró, ti ikọ̀ ìpínlẹ̀ Adamawa, CP Dankombo Morris, ti kí aṣojú láti inú ẹgbẹ́ àwọn Akọ̀ròyìn (NUJ), ikọ̀ ti…
button