Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN

This is a category for featured story

Ààrẹ Tinubu túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ lóri ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ láàrin ẹlẹ́sìn,…

Adarí Nàìjíríà, Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ lóri ìṣàgbélárugẹ àjọṣepọ̀ ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ láàrin Àwọn ẹlẹ́sìn, ìgbàmọ́ra, àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ jákèjádò lágbàáyé Ààrẹ naa…

Ọdún Egúngún Lágbayé Ti 2025: Makinde Pinnu Ìgbélárugẹ Àṣà Fún Àgbéga Ọrọ̀ Ajé

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti tẹnu mọ́ pé ìṣèjọba òun yóò máa ṣe atilẹyin fún ìmúgbòòrò àṣà àti ìgbélárugẹ ìṣẹ̀dálẹ̀ ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Gómìnà ló síṣọ lójú ọ̀rọ̀ yìí níbi àṣèkágbá ọdún Egúngún Lágbayé ti ọdún 2025, ayẹyẹ…

Orílè-èdè Nàìjíríà Darapọ̀ Mọ́ Báǹkì Ilẹ̀ Gẹẹsi Fún Àtúnṣe Àti Ìtèsíwájú

Wọ́n ti gba orilẹ̀-ède Nàìjíríà wọlé bí ọmọ ẹgbẹ́ bánkì àjọ European Bank for Reconstruction and Development (EBRD). Mínísítà ètò owó àti Olùdarí ètò ọrọ̀ ajé, ọ̀gbẹ́ni Wale Ẹdun, ló sọ eléyìí di mímọ̀ níbi Ìpàdé àjọ EBRD ọdún 2025…

Ààrẹ Nàìjíríà Tí Fọwọ́sí Gbígba Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Igbó ‎

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí fọwọ́sí ìgbanísíṣẹ́ tí àwọn ẹ̀ṣọ́ igbó gẹ́gẹ́bí isọdọtun àwọn ìlànà orílẹ̀-èdè láti ní Ààbò àti gbá àwọn igbó Nàìjíríà pàdà lọwọ́ àwọn ọ̀daràn àti àwọn arufín ilú. ‎ ‎ Ìpinnu náà ní èròngbà látí tẹra mọ iṣẹ́…
button