Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Ẹ Ri Wí Pé Ẹ Mọ Iṣé Yìí Dájú: Mínísítà Fún Ètò Ìlera.
Mínísítà fún ètò ìlera fun ìpínlẹ̀ Dọ́kítà Salako ti rọ àwọn òṣìṣẹ́ ìlera láti rí wí pé wọn mọ iṣé wọn de ojú ààmì o sí da wọn lójú.
Salako sọ èyí di mímọ̀ ni ìlú Abuja níbi, ayẹyẹ ibura fún àwọn òṣìṣẹ́ agbègbè àwọn ènìyàn…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia Ṣe Ìkìlọ Fún Àwọn Ènìyàn Ìpínlẹ̀ Náà Nípa Ìtọ́jú Ojú Tí Kò Tọ̀nà.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia Alex Otti ti pé àkíyèsí àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Abia latari bi wọn ṣe n se ìtọjú ojú wọn ní ọna ti ko tana.
Gómìnà ni èyìn leè ṣe òkùnfà kí ojú náà fò pátápátá Lai sí àtúnṣe.
Ó ṣe ìkìlọ náà ni ọjọ́rú lásìkò ìfilọ́lẹ̀…
Àjọ Ìlera Lágbayé Ṣe Ẹ̀tọ̀ Ìlànà Ọ̀nà Àbayọ Fún Àìsàn Ìgbóná.
Àjọ elẹ́tọ̀ àgbáyé fún ìlera (WHO) ti ṣe àwọn ètò àti ìlànà fún ọnà àbayọ lórí àìsàn Ìgbóná àkókó irú rẹ.
Wọn ní ìtọ́jú lásìkò, gbaradi lásìkò, ṣiṣe àkíyèsí lásìkò àti ìtọjú to péye láti ọ̀dọ̀ àwọn Akosemósè yóò mú kí àìsàn náà di ohun…
Àyájọ́ Ìlera Àgbáyé : Àjọ WHO Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Dẹ́kun Ikú Rèwe-rèwe
Gẹ́gẹ́ bí Orílẹ̀-èdè Naijiria se darapọ̀ mọ́ ojúgbà rẹ̀ ní àgbáyé ní àyájọ́ Ìlera ti ọdún 2025, àjọ WHO ti pè fún ìgbésẹ̀ ọ̀tun láti dènà ikú ní rèwe-rèwe ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Níbi…
Kọ́mísọ́nà Se Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Tí Ó Lùgbàdì Ìjàm̀bá Iná Ní Ìpínlẹ̀ Kogi
Kọmísọ́nà Fún Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Àti Ìdàgbàsókè Àwùjọ, Arábìnrin Fatimah Momoh ti nawọ́ àánú léyìí tí ó se ìrànlọ́wọ́ fún Arábìnrin Soje Ogori, tí ó jẹ́ olùgbé Ogori-Magongo, ẹni tí iná jó ilé rẹ̀ ní…
Àjọ NHIA Se Àtúntò Tí Yóò Fún Ọ̀tọ̀ǹkùlú Ìlú Ní Ànfààní Ètò Ìlera Tí Ó Péye
Àjọ NHIA ti se àmúlò àwọn àtúntò tí ó wáyé èyí tí yóò fún àwọn ènìyàn ní ànfàànì ètò ìlera tí ó péye jákè-jádò Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Gẹ́gẹ́ bí ìfiléde kan tí ó wáyé ní ọjọ́ Àìkú…
Àwọn ọmọ ogun ojú omi Nàìjíríà pèsè ètò ìwòsàn ọ̀fẹ́ ní Bayelsa
Àwọn ọmọ ogun ojú omi Nàìjíríà SOROH, NNS SOROH, ti pèsè ètò ìwòsàn ọ̀fẹ́ fún àwọn aládùúgbò Tombia tó ju ẹgbẹ̀rún méjì lọ, ní ìjọba ìbílẹ̀ Yenagoa, ní́ ìpínlẹ̀ Bayelsa , Gusu Nàìjíríà.
Ajagun…
Nàìjíríà gba àjẹsára Men5CV láti kojú àjàkálẹ̀ ààrùn yínrùnyínrùn
Nàìjíríà ti gba òògùn àjẹsára tuntun pentavalent meningococcal alápapọ̀ pẹ̀lú (Men5CV), tí ó lé ní mílíọ́nù kan láti ilé iṣẹ́ Gavi tí ń ṣe àjẹsára lágbàáyé láti kojú àjàkálẹ̀ ààrùn tó burújàì…
Ìlera Ọpọlọ: Ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna Ṣe Àtúnṣe Àwọn Ilé ìwòsan ìjọba Tọ Le Ni Márùndinotalenigba.
Nínú èròngbà láti ṣe àtúnṣe àwọn ilé ìwòsan ìjọba káàkiri ìpínlẹ̀ Kaduna, ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna ti ṣe àtúnṣe àwọn ilé ìwòsan márùndinotalenigba. Ìdàgbàsókè ọtún
Èyí di ṣiṣe láti mú ìdàgbàsókè ba ètò ìlera ni ìpínlẹ̀.
Níbi ifọrọwọrọ…
Orílè-èdè Nàìjíríà Gbà Abẹ́rẹ́ àjẹsára Men5CV Láti Dènà Àìsàn YírùnYírùn Ti O Gbòde Kan.
Orílè-èdè Nàìjíríà tí gbà o kéré ju, Mílíọ̀nù kan abẹ́rẹ́ àjẹsára Men5CV èyí tí yóò dènà àìsàn YírùnYírùn, ti o Gbòde Kan báyìí.
Àìsàn YírùnYírùn yìí ti gbà emi àwọn ènìyàn ti o to Aadọrin ti o sí ti ṣe àkóbá fún àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè…