Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
NAFDAC tẹnumọ́ ìpinnu rẹ̀ láti ṣe àdínkù òògùn ayédèrú, àwọn ohun èlò oúnjẹ
Ilé iṣẹ́ tí ń mójútó ìṣàkóso oúnjẹ àti òògùn (NAFDAC) ti túnbọ̀ tẹnumọ́ ìpinnu rẹ̀ bẹ́gi dínà kátàkárà tí kò bófin mu láti ṣe àdínkù ayédèrú, àwọn ohun èlò oúnjẹ àti òògùn lórílẹ̀-èdè.
O fi idi…
Àjọ Tó Ń Mójú Tó Ètò Ìlera Ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà NCDC, Ni Àkọsílẹ Àìsían Lassa Fever Pọ Lọdun 2023.
Àjọ tó ń mójú tó ètò ìlera ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NCDC) ni lọdun to kọja lọ yìí 2023 àwọn ni àkọsílẹ àìsían Lassa Fever nínú ọ̀sẹ̀ ọ̀kànlẹ́láàdọ́ta.
Nínú èro ayelujara fún àjọ NCDC ni ìròyìn náà ti di mímọ ní ọjọ́ ìsinmi ní ìlú Abuja.…
Ọtí Mímu Di Èèwọ̀ Fún Àwọn Aláboyún- Àjọ Tí Ó Ń Pọn Ọtí Ẹlẹ́rìndòdò Sèkìlọ̀
Àjọ tí ó ń pọn ọtí ẹlẹ́rìndòdò Maltina àti Malta ti sàgbékalẹ̀ ìpolongo láti se ìkìlọ̀ fún àwọn aláboyún kúrò níbi ọtí mímu nítorí ewu ńlá tí ó wà nínú ìsesí bẹ́ẹ̀
Ẹka ìfọ̀rọ̀léde àwọn ilé…
Ẹgbẹ́ Àjọ Onímọ̀ Ìsègùn Òyìnbó Fí Ohun Èlò Ìtura Ta Àwọn Tí O Fi Ara Káásá Lọ́rẹ…
Alága àpapọ̀ fún ẹgbẹ́ Onímọ̀ Ìsègùn Òyìnbó ti fi àwọn ohun èlò atunilára ta àwọn tí o fi arapa nínú ìkọlù tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Plateau
Ìgbésẹ̀ náà wáyé láti se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí o fi…
Àjọ NDDC Yóò Bẹ̀rẹ̀ Ìwòsàn Ọ̀fẹ́ Ní Ẹkùn Niger Delta
Àjọ NDDC ti tẹ́pẹpẹ ìgbáradì rẹ̀ láti bẹ̀rẹ̀ ìwòsàn ọ̀fẹ́ èyí tí yóò jẹ́ ànfààní fún àwọn ènìyàn ìgbèríko ní ẹkùn Niger Delta
Alákòóso àjọ náà fún ètò Ẹ̀kọ́ , Ìlera àti Ìdàgbàsókè…
Ìyàwó gómìnà Kebbi pín àwọn ohun èlò, owó fún àwọn ọmọ tí wọ́n bí wọ ọdùn tuntun
Ìyàwó gómìnà ìpínlẹ̀ Kebbi, Hajiya Nafisa Idris, ti pín owó ati àwọn aṣọ ọmọ tuntun fún àwọn ọmọ tuntun méjì àti ìbẹta kan tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìnníí, oṣù kìnníí, ní ìsọ̀rí àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé Fati…
Ẹgbẹ́ pinnu láti ṣàmójútó àwọn ilé-ìwòsàn ní àwọn ìgbèríko
Ẹgbẹ́ kan lábẹ asia Ẹgbẹ́ Àwùjọ Ará ìlú (CSOs), àti ètò ibùdó ilé ìwòsàn alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti gbìmọ̀ láti dá ìsọ̀rí tí yóò máa mójútó èto àwọn ilé-ìwòsàn, pàápàá jùlọ ní àwọn ìgbèríko.
Ninu alaye…
Ìgbáyégbádùn Àwọn Dókítà Onímọ̀ Ìsègùn Òyìnbó Se Pàtàkì- Ẹgbẹ́ Àjọ Náà Tẹ́…
Ẹgbẹ́ Àwọn Dókítà Onímọ̀ Ìsègùn Òyìnbó ẹka ti ìpínlẹ̀ Ogun ti fi ẹ̀dùn ọkàn hàn látàrí ìgbé ayé ìlekoko tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àjọ náà ń gbé pẹ̀lú iṣẹ́ àsekúdórógbó látàrí iná mọ̀nà-mọ́ná tí ń se…
Àmójútó Tí Ó Péye Se Pàtàkì Fún Àwọn Tí Ó Ní Ìpèníjà Ara- Àjọ Kan Pàrọwà Sí…
Àjọ kan tí kì í se tí ìjọba tí ó fi Ìpínlẹ̀ Bauchi se ibùjòkó ti pàrọwà sí ìjọba láti se àmójútó tí ó péye fún àwọn ọmọdé tí ó ní ìpèníjà ara, ní papàá jùlọ fún ètò ẹ̀kọ́ àti ìlera
…
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Sí Ilé Ìwòsàn Ńlá Ní Ikorodu
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin, Tajudeen Abass ti sí ilé ìwòsàn ńlá tí ó sì sọ ọ́ di lílò ní ọjọ́ Ìsẹ́gun, èyí tí ó gba bẹ́ẹ̀dì ìwòsàn ọgọ́rin ní Imọta, Ikorodu, Ìpínlẹ̀ Eko
Ọ̀gbẹ́ni Babajimi Benson,…