Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Ìjọba Àpapọ̀ yóò Fi Gbèdéke Sí Owó Tí Wọn Yóò Máa Ta Oògùn Lílò Láìpẹ́ Jọjọ…
Ìjọba àpapọ̀ yóò pàṣẹ láti fi gbèdéke sí iye tí wọn yóò máa ta oògùn lílò, èyí tí yóò fún àwọn ènìyàn ní ànfààní ríra oògùn fún àlàáfíà tí ó péye
Mínísítà Fún Ètò Ìlera, Ali Pate…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kogi sàlékún Àjẹmọ́nú Owó Fún Àwọn Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Onímọ̀ Ìsègùn…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kogi, Yahaya Bello ti buwọ́lu àjẹmọ́nú owó tí yóò jẹ́ sísan fún àwọn dókítà onímọ̀ ìsègùn òyìnbó àti àwọn elétò ìlera yókù ní ìpínlẹ̀ kogi láti se kóríyá fún wọn
Gómìnà fi…
Ìpínlẹ̀ Benin Gbà Àwọn Ògùn Fún Ìtọjú Ibà Èyí To Lè Ní Ẹgbẹrun Méjì.
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Benin ti gbà àwọn ògùn fún ìtọ́jú àìsàn ibà èyí tó lè ní ẹgbẹrun méjì .
Ogun naa ni wọn gbà láti papako Òfurufú Cotonou , lilọ àwọn ògùn yìí yóò sì bẹ̀rẹ̀ ní oṣù Kejì Ọdún yìí.
Níbi ayẹyẹ mọ gbe iṣẹ le ọ lọwọ ni…
Gombe: NSCDC ké gbàjarì lórí àkóràn ààrùn tí kò gbóògùn láàrin àwọn obìnrin
Adarí ẹgbẹ́ tí ń mójútó ààbò Nàìjíríà àti ìdáàbòbò ará ìlú (NSCDC), ti ìpínlẹ̀ Gombe ti ké gbàjarì, pé àwọn ọmọ bìnrin kan tí wọ́n ti kó ààrùn kògbóògùn HIV/AIDS ti ya wọ ìpínlẹ̀ Gombe, olú ìlú…
Àjọ Ọmọ Ogun Òfurufú Sàgbékalẹ̀ Ìwòsàn Ọ̀fẹ́ Fún Àwọn Ènìyàn Ìlú Benue
Àjọ Ọmọ Ogun sàgbékalẹ̀ ìwòsàn ọ̀fẹ́ ní ọjọ́ Ẹtì, ní ìlú Makurdi fún àwọn òsìṣẹ́ fẹ̀yìntì àjọ náà tí ó wà ní olú ìlú ìpínlẹ̀ Benue àti àgbègbè rẹ̀
Ìgbésẹ̀ náà wà lára àlàkalẹ̀ àjọ náà fún…
Àjọ Aláàánú Ọmọnìyàn kan Pèsè Ohun Èlò Fún Àwọn Tí Ìdágìrì Lé Kúrò Ní Ìletò…
Àjọ kan tí a mọ̀ sí Gbenga Samuel-wemimo ti sàgbékalẹ̀ àwọn ohun amáyéderùn fún àwọn ibùdó mẹ́rin kan níbi tí àwọn ènìyàn tí wàhálà lé kúrò ní ibùgbé wọn fi ara sunko sí.
Ìfiléde náà wáyé…
Ìpínlẹ̀ Kebbi Ti Ná Bílíọ̀nù Márùn-ún Náírà Láti Ṣe Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Àgbẹ̀.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kebbi sọ wí pé àwọn tí na Bílíọ̀nù Márùn-ún Náírà láti fi ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn àgbẹ̀ ni ìpínlẹ̀ náà.
Wọn ní lára owó yìí ni àwon tí pèsè ètò ààbò fún àwọn àgbẹ̀ pẹ̀lú.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kebbi Dọ́kítà Mohammed Idris lo sọ…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ń Pàdánù Àwọn Òṣìṣẹ́ Ilera Látàrí Àìsían Ikọ́ Ife.:Àwọn Onimọ.
Adarí àgbà pátápátá fún ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú ìlera, Dọ́kítà Alobu Isaac ti je ko di mimo wí pé Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pàdánù àwọn elétò ìlera látàrí àìsían ikọ́ ife.
Dọ́kítà ni eleyii n ṣẹlẹ̀ látàrí wí pé kò sí àwọn ohun èlò àti ògùn ti…
Àjọ KADCHMA Yóò Pèsè Ètò Ìtọ́jú Òfé Fún Àwọn Tó kò Ni Agbára To Ni Ìpínlẹ̀ Kaduna.
Àjọ tó ń ṣe akojọpọ nipa ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Kaduna (KADCHMA) Pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ Clinton Health Access ni àwọn yóò pèsè ètò ìtọ́jú ìlera ọ̀fẹ́ fún àwọn ti kọ ni lágbára tó láti ṣe ìtọ́jú ará wọn nipasẹ owó , láàrin ìpínlẹ̀ náà.
Wọn awọn…
Àjọ NPC Ti Bẹrẹ Ètò Kíkà Awọn Ènìyàn Nípa Ìlera Ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì
Àjọ tó ń ka àwọn ènìyàn ní ìpínlẹ̀ Ekiti (NPC) ti bẹ̀rẹ̀ ètò kíka àwọn ènìyàn nípá ilera ni ìpínlẹ̀ náà ni Ọjọ́bọ̀.
Àjọ náà ni ètò kika náà yóò dé gbogbo ìjọba ìbílẹ̀ merindinlogun to wa ni ìpínlẹ̀ Èkìtì.
Wọn ní ètò kika náà yóò bèrè…