Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Àìsàn Ikọ́ Féére Yóò Di Ohun Ìtàn Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà- Ìjọba Àpapọ̀ Sọ̀rọ̀…

Ìfikùnlukùn pẹ̀lú àwọn aráìlú àti lílo ohun èlò ìgbàlódé ni yóò jẹ́ ọ̀nà àbáyọ pàtàkì láti tán ìsòro àrun ikọ́ féére ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí ìgbìyànjú tí ó wáyé èyí tí ó mú kí…

Ìpínlẹ̀ Delta Fọwọ́sọwọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àjọ NEMSAS Fún Ìdàgbàsókè Ọpọlọ Àwọn Ọmọdé Ni Ìpínlẹ̀ Náà.

Nínú igbiyanju ijoba ìpínlẹ̀ Delta láti rí wí àwọn ọmọdé ri ìtọ́jú tó péye pàápàá jùlọ fún ìdàgbàsókè ọpọlọ àwọn ọmọdé. ìjọba ìpínlẹ̀ Delta fọwọ́sọwọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àjọ NEMSAS niyen Àjọ to n mójú tó ìtọ́jú àti ìdàgbàsókè ọpọlọ. Dọ́kítà…

Ẹ Fòpin Sí Ìfipá Báni Lòpọ̀ Àti Àsìlò Ọmọnìyàn Láwùjọ- Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Kan Kégbàjarè

Agbẹjọ́rò tí ó tún jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn, Toyin Taiwo-Ojo ti kégbàjarè gẹ́gẹ́ bí ìwà ìfipábánilòpọ̀ àti àsìlò ọmọnìyàn se gbilẹ̀ láwùjọ Ó fi àìdùnnú ọkàn hàn ní ọjọ́ Àbámẹ́ta nígbà tí ó…
button