Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
This is a category for entertainment news
Akọrin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Ireland, Sinéad O’Connor Kú Ní Ẹni Ọdún-Mẹ́rin-dín-lọ́gọ́ta
Gbajúgbajà akọrin Orílẹ̀-èdè Ireland, Sinéad O’Connor, ti kú ní ẹni ọdún-mẹ́rin-dín lọ́gọ́ta, ọdún kan lẹ́yin ti ọmọ rẹ-Shane náà jẹ Ọlọ́run ní ìpè.
Ìdílé akọrin náà ló kéde eyi ni ọjọ Ojoru lori iroyin ti ibile, iwe…
Calm Down ‘ Orin Rema Gbayì Ju Gbogbo Orin Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Tókù Lọ Nínú Ìtàn Amẹ́ríkà
Gbajúmọ̀ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè yìí, Divine Ikubor, ti ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́, Rema, tún ti fi ìtàn balẹ̀.
Orin rẹ̀ tí won fẹ́ràn ‘Calm Down ni wọn ńkọ, ti wọ́n n gbọ́ jùlọ nínú orin ilẹ Adúláwọ̀ ni orílẹ̀-èdè Amerika. Orin náà le…
BurnaBoy Fèsì Fún Davido
Akọrin omo Nàìjíríà , Damini Ogulu, ti wọ́n mọ̀ sí Burna Boy,ti sọ̀rọ̀ nípa orúkọ tí wọn fún nínú eré orin - “Olóngbò tuntun "- new cat.
Burna boy so pé òun rí inagijẹ náà bí eni to ṣẹṣẹ bẹrẹ orin ati pé òun rí bí anfààní nla…
Òṣèré Tíátà Kan Dì Akọ̀wé Ayẹyẹ Ẹgbẹ́ Ìyàwó Àwọn Sẹ́nétọ̀
Gbajúmò òsèrébirìn kan, Regina Daniels ni wọ́n ti yàn gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé ayẹyẹ ẹgbẹ́ Ìyàwó àwọn Seneto ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ìyáàfin Regina kéde ìyànsípò rẹ̀ ní orí òpó instagramu ní ọjọ́ Ọjọ́rú, oṣù keje ọdún 2023. Ó…
Wizkid Se Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìbí Ọdún Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n
Gbajúgbajà akọrin ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n ń pè ni Wizkid fi kún ọjọ́ ìbí rẹ̀ ní ọjọ́ àìkú. Akọrin "More Love, àti Less Ego’ crooner" pé ẹni ọdún Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n lókè erùpẹ̀.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ olólùfẹ́ rẹ ló ti gba orí ẹrọ…
Ìjìyà Tí Ó Tọ́ Sí Ẹní Fí Ipá Báni Lọ̀pọ̀ Náà Ló Tọ́ Sí Ẹní Tó Bá Parọ́ Wí Pé Wọn Bá Òun Lòpọ̀…
Gbajugbaja òṣèré Obìnrin Uche Jambo sọ wí pé ìjìyà kànnà lo tọ sí ẹni ti o ba parọ́ wí pé wọn fi ipa bá òun lòpọ̀ àti ẹni tí o ba wù ìwà ìbàjẹ́ náà.
Àgbà òṣèré Obìnrin yìí sọ èyí látàrí ẹ̀sùn tí obìnrin kan fi kan agbá bóòlù tẹ́lẹ̀…
Rikkie Valerie Kolle, Di Obìnrin Arẹwà Jùlọ Ní Orílẹ̀-èdè Netherland
Obìnrín ọmọ orílẹ̀-èdè Netherland tó ní àmúyẹ obìnrin àti ọkùnrin, Rikkie Valerie Kolle, ti gba adé Olúborí obìnrin tó dára jù ti "Miss Netherland beauty pageant" fun ìgbà àkọ́kọ́ nínú ìtàn.
Ọmọ ọdún mejìlélógún náà fi ìtàn…
Macaroni Gba Ẹ̀bùn Ọkọ̀ Ayọ́kẹ́lẹ́ Tuntun
Adẹ́rìn-ín pòsónú ọmọ Nàìjíríà, Debo Adebayọ tí gbogbo ayé mọ̀ sí Macaroni ti gba ẹ̀bùn ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tuntun fún bí ó ti se fakọyọ jùlọ.
Àwọn gbajúgbajà òsèré bíi Kiekie, Toyin Abraham, Denrele Edun,…
Regina Daniels Se Ayẹyẹ Ìyànsípò Ọkọ Rẹ̀ Padà Sí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin
Gbajú-gbajà òsèré, Regina Daniels, ìyàwó onísòwò ńlá, Ned Nwoko ti se ayẹyẹ ìyànsípò ọkọ rẹ̀ padà sí ilè ìgbìmọ̀ asòfin àgbà ní ìlú Abuja.
Wọ́n búra fún Nwoko ni ọjọ kẹtala osu kẹfà ọdun 2023 láti…
Ìlúmọ̀ọ́ká Ọmọbíbí Ilẹ̀ Amẹ́ríkà Bí Ọmọ Ẹlẹ́ẹ̀kejì
Ìlúmọ̀ọ́ká ọmọbíbí ilẹ̀ Amẹrika, Megham Trainor ti kéde àmójúbà ọmọ tuntun jòjòló ẹlẹ́ẹ̀kejì lórí ẹ̀rọ ayélujára . Ó dáwọ̀ọ́ ìdùnnú pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ látàrí bí wọ́n se bí ọmọ tuntun sáyé ní ọjọ́ kìníí osù…